Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Oro Kan Soso

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Oruko Tuntun โ€ข โฑ๏ธ 8:58
๐ŸŽต 3157 characters
โฑ๏ธ 8:58 duration
๐Ÿ†” ID: 10398343

๐Ÿ“œ Lyrics

Oro kan soso
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Beeni mo wi
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Oro laseda fi d'aye at'orun
Ohun gbogbo to wa ninu e, oro lo fi da
B'aye at'orun ba yi pada, oro l'Olorun yio wa titi lai
Tori oro ledidi ohun gbogbo
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Oro lagbara e wa wo'di oro aye
Ohun t'aye n pe loro ni gbolohun
Ninu oro aye ni won n so ofo
Ninu oro won ni, ase
Ohun oro aye n se fun aye
'Jamba lo po ninu won
Oruko t'aye ba p'oro ni yio je
Ibi ni won fi n se fun 'ra won
Eda gbogbo ti n gb'aye e ma ba mi bo o
Ibudoko ero to n lo si irin ajo
Laperosoko ti n p'ariwo
E wole, hundred naira lowo ori enikan
Onikaluku wole soko
Loko ba kun ni won ba si
Won m'ori le irin ajo won
Igba t'an mi a gb'owo oko tan pata
Baba kan lo ko to lohun o ni san'wo pe
O san hundred naira, o fe gba forty naira pada
Gbogbo ero to mbe ninu oko, won ko ha! wipe baba se bee ti gbo tele
Conductor lohun o ni gba laabo, baba lohun o ni won kun
Enikan ninu oko lohun a fi kun
Baba ba ni ko ni dara f'eni ba fi kun
Gbogbo ero to mbe ninu oko ba gb'enu won dake
Igba baba de 'bi to n lo
Lo ba wo conductor sokale loko, lo ba ni o gbe
Ka to wi, ka to fo, ero ti pe le won lori
Ijamba laye ma fi n wa (beeni)
B'agbara aye ba ti n gun won (e o ni se won)
B'ika ba n gun eniyan ibi, won a maa to'ja tase kiri beeni
Oro ni won fi n ja, e wa wo'di oro t'aye n pon le
Lo ba p'ase lati 'nu oro, t'a wa ninu Olorun ti a ko ri
Ko to wi tan, conductor ti bo'so sonu
Lo ba mo'ri le 'gbo
S'e ti r'aye oro agbara aye, opelope arakunrin kan
T'o m be ninu oko to j'omo Olorun, to m'oro iseda
To da aye, to d'ohun gbogbo
Oro Olorun to nipa oro eyi ti a ti ko wipe, ko s'ohun ija kan ti a se si o ti yio pa o lara
Ati pe t'aa leni naa, ti n wi, to si n se, nigba ti Oluwa ko p'ase re o
Nitorina, ni oruko Jesu Olugbala, conductor pada wa 'bi, wo'so k'ori e si pe
Lara ba ro baba oloro aye, a b'e o r'oro to n gb'oro mi
Bi ko ba se ti Jesu, opo eda lo ti d'eja ko s'awon won
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
Eniyan inu aye, e je k'a fura o
Satani n s'oro bi agbon
Elomiran ki a to bi won o, lowo awon ota ti te won
Elomiran nigba t'a bi won tan, laarin egbe, nibi ise, owo ika t'a gbe leni lori ta o mo, lorisirisi ijamba ti n se ni
E je ka gb'adura eniyan o
K'aye ma f'oro won tun ni da
Mo f'owo d'eleda mi mu
K'ori mi ma gba 'bode oro o
Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro iseda, o so won di're pada, oro o
Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro iseda, o so won di're pada, oro o
Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Oro iseda, o so won di're pada, oro o

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:38.65] Oro kan soso
[00:39.56] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[00:51.92] Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[00:58.79] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[01:04.83] Beeni mo wi
[01:05.86] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[01:18.14] Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[01:24.38] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[01:33.13] Oro laseda fi d'aye at'orun
[01:35.72] Ohun gbogbo to wa ninu e, oro lo fi da
[01:39.14] B'aye at'orun ba yi pada, oro l'Olorun yio wa titi lai
[01:42.30] Tori oro ledidi ohun gbogbo
[01:52.68] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[02:04.07] Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[02:11.13] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[02:18.13] Oro lagbara e wa wo'di oro aye
[02:22.52] Ohun t'aye n pe loro ni gbolohun
[02:24.81] Ninu oro aye ni won n so ofo
[02:28.59] Ninu oro won ni, ase
[02:31.81] Ohun oro aye n se fun aye
[02:34.93] 'Jamba lo po ninu won
[02:38.18] Oruko t'aye ba p'oro ni yio je
[02:41.15] Ibi ni won fi n se fun 'ra won
[02:44.82] Eda gbogbo ti n gb'aye e ma ba mi bo o
[02:51.52] Ibudoko ero to n lo si irin ajo
[02:54.98] Laperosoko ti n p'ariwo
[02:58.19] E wole, hundred naira lowo ori enikan
[03:04.70] Onikaluku wole soko
[03:08.03] Loko ba kun ni won ba si
[03:11.26] Won m'ori le irin ajo won
[03:17.86] Igba t'an mi a gb'owo oko tan pata
[03:21.19] Baba kan lo ko to lohun o ni san'wo pe
[03:24.32] O san hundred naira, o fe gba forty naira pada
[03:31.48] Gbogbo ero to mbe ninu oko, won ko ha! wipe baba se bee ti gbo tele
[03:37.78] Conductor lohun o ni gba laabo, baba lohun o ni won kun
[03:44.06] Enikan ninu oko lohun a fi kun
[03:50.83] Baba ba ni ko ni dara f'eni ba fi kun
[03:57.33] Gbogbo ero to mbe ninu oko ba gb'enu won dake
[04:03.64] Igba baba de 'bi to n lo
[04:07.77] Lo ba wo conductor sokale loko, lo ba ni o gbe
[04:13.95] Ka to wi, ka to fo, ero ti pe le won lori
[04:23.80] Ijamba laye ma fi n wa (beeni)
[04:27.09] B'agbara aye ba ti n gun won (e o ni se won)
[04:30.23] B'ika ba n gun eniyan ibi, won a maa to'ja tase kiri beeni
[04:36.46] Oro ni won fi n ja, e wa wo'di oro t'aye n pon le
[04:43.41] Lo ba p'ase lati 'nu oro, t'a wa ninu Olorun ti a ko ri
[04:49.47] Ko to wi tan, conductor ti bo'so sonu
[04:53.48] Lo ba mo'ri le 'gbo
[04:56.61] S'e ti r'aye oro agbara aye, opelope arakunrin kan
[05:02.68] T'o m be ninu oko to j'omo Olorun, to m'oro iseda
[05:09.51] To da aye, to d'ohun gbogbo
[05:12.85] Oro Olorun to nipa oro eyi ti a ti ko wipe, ko s'ohun ija kan ti a se si o ti yio pa o lara
[05:25.84] Ati pe t'aa leni naa, ti n wi, to si n se, nigba ti Oluwa ko p'ase re o
[05:37.55] Nitorina, ni oruko Jesu Olugbala, conductor pada wa 'bi, wo'so k'ori e si pe
[05:56.77] Lara ba ro baba oloro aye, a b'e o r'oro to n gb'oro mi
[05:57.57] Bi ko ba se ti Jesu, opo eda lo ti d'eja ko s'awon won
[06:04.14] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[06:17.37] Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[06:24.07] Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso
[06:45.38] Eniyan inu aye, e je k'a fura o
[06:48.53] Satani n s'oro bi agbon
[06:51.73] Elomiran ki a to bi won o, lowo awon ota ti te won
[06:58.48] Elomiran nigba t'a bi won tan, laarin egbe, nibi ise, owo ika t'a gbe leni lori ta o mo, lorisirisi ijamba ti n se ni
[07:14.96] E je ka gb'adura eniyan o
[07:21.62] K'aye ma f'oro won tun ni da
[07:27.77] Mo f'owo d'eleda mi mu
[07:34.12] K'ori mi ma gba 'bode oro o
[07:38.56] Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
[07:48.70] Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
[07:52.67] Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[07:58.93] Oro iseda, o so won di're pada, oro o
[08:05.36] Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
[08:12.96] Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
[08:19.21] Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[08:25.99] Oro iseda, o so won di're pada, oro o
[08:32.73] Oro kan soso to s'eda aye e, oro kan ni
[08:40.22] Oro kan soso to n gbe oro mi, oro kan soso
[08:45.27] Gbogbo ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
[08:51.92] Oro iseda, o so won di're pada, oro o
[08:56.33]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings