Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Wá Wọlé & Worshiṕ (Live)

👤 Sola Allyson 🎼 ÌRÌ (The Album Live) ⏱️ 10:11
🎵 867 characters
⏱️ 10:11 duration
🆔 ID: 10413673

📜 Lyrics

Eni o mobi ti mo ti n bo
Ko le dami lejo ibi mo de duro
Eni o mobi mo la koja
Ko le ro mi lejo ibi mo nre lowo, lowo
Oluwa lo mo'bi mo nre
Lo fi mumi labi mo la koja

Mo dupe ooo
Mo yege
Imole tan sona mi
Moti bo oo
Moti bo oo
Moti bo

Wa wole ooo
Maa bo omo
Ona imole yi npeni
Wa je ninu aadun yen oo (nigba meji)

Eni o ba gbe'nu okunkun
Kole mo riri imole rara
Eni ebi opa ri
Kole more riri ipese ounje
Eni o ba jiya
Kole mo riri ohun ara nje

Ibi mode
Oluwa lo se
Oro aye mi to ku
Mo fi le lowo
Ohun oju mi ri
O je nmo p'alanu loluwa

Ema lemi lere
Eni lani solododo
Ma de 'bi maa de oo
Ona mi atubo la peregede

E o le dami duro
Eni mumi de 'bi alagbara ni
Ma de 'bi maa de oo
Ona mi atubo la peregede

Eyi to se koko nibe
Nipe kaa tona imole laye n'bi
Eni waye lai m'olu, lai mo 'mole
Inu okukun ayeraye lo ngbe
Emi npinu lati rina imole
Aanu yami ya'ya lona mi

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings