Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Tension (Remix)

👤 Ykb 🎼 Tension (Remix) ⏱️ 2:14
🎵 1637 characters
⏱️ 2:14 duration
🆔 ID: 10958097

📜 Lyrics

Nope
No word, Ginit
You don't know the streets like we do
Nope (Niphkeys)

Igi to ba mu ọmọ ile iwe sanigbo o
Awa dẹ ma tension wọn mọta wa ni jo
K'awa ṣá ma wo wọn ni iran, ka ma carry go
Emi ọmọ ara má sanwo, kin le tun duro wo?

Ayy, awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa l'agba o, mi o ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi
Awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?

Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
Awa o de le fọ fun wọn, ọmọ ita wa ni gbo
K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o

Ahn-ahn, fi lẹ bẹ, make them talk
Ṣébí na why we get am
I go dance, I go flex
Ṣébí na why we get am

No comedy-dy, what I no get
Ki lo ṣe àwọn nonetity? (Eh)
Them dey call me celebrity, eh
But I be bulldozer (ah-ah)
I no get pretty Q (I be bulldozer)
Ọgbẹni, commot for road

Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa lọ mọ o, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi o?
Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?

Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
Awa o dẹ le fọ fun wọn, mọta wa ni gbo (e gbe, gbe, gbe)
K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go o
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
Oh, ah, Kila fagbo ẹlẹyin, ahn-ahn
Kila n fagbo ẹlẹyin mi oke o
Kila fagbo ẹlẹyin mi oke o
'Sufu baby, ta ba sin wọn d'oke
Yusufu, baby o, ama sin wọn de oke o

⏱️ Synced Lyrics

[00:00.63] Nope
[00:04.25] No word, Ginit
[00:07.58] You don't know the streets like we do
[00:11.74] Nope (Niphkeys)
[00:14.78] Igi to ba mu ọmọ ile iwe sanigbo o
[00:18.44] Awa dẹ ma tension wọn mọta wa ni jo
[00:21.74] K'awa ṣá ma wo wọn ni iran, ka ma carry go
[00:25.29] Emi ọmọ ara má sanwo, kin le tun duro wo?
[00:29.30] Ayy, awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
[00:33.35] Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
[00:36.84] Awa l'agba o, mi o ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi
[00:40.41] Awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
[00:42.83] Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
[00:46.46] Awa o de le fọ fun wọn, ọmọ ita wa ni gbo
[00:49.95] K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go
[00:53.45] K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
[00:56.91] Ahn-ahn, fi lẹ bẹ, make them talk
[00:59.97] Ṣébí na why we get am
[01:01.80] I go dance, I go flex
[01:03.49] Ṣébí na why we get am
[01:05.36] No comedy-dy, what I no get
[01:08.59] Ki lo ṣe àwọn nonetity? (Eh)
[01:10.18] Them dey call me celebrity, eh
[01:12.32] But I be bulldozer (ah-ah)
[01:14.33] I no get pretty Q (I be bulldozer)
[01:17.38] Ọgbẹni, commot for road
[01:18.96] Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
[01:22.54] Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
[01:26.07] Awa lọ mọ o, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi o?
[01:29.52] Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
[01:32.06] Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
[01:35.58] Awa o dẹ le fọ fun wọn, mọta wa ni gbo (e gbe, gbe, gbe)
[01:39.07] K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go o
[01:42.55] K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
[01:46.13] K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
[01:49.54] Oh, ah, Kila fagbo ẹlẹyin, ahn-ahn
[01:54.91] Kila n fagbo ẹlẹyin mi oke o
[01:58.59] Kila fagbo ẹlẹyin mi oke o
[02:01.74] 'Sufu baby, ta ba sin wọn d'oke
[02:05.19] Yusufu, baby o, ama sin wọn de oke o
[02:10.33]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings