Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Abo Mi Kodara

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Alagbara โ€ข โฑ๏ธ 6:03
๐ŸŽต 577 characters
โฑ๏ธ 6:03 duration
๐Ÿ†” ID: 11143095

๐Ÿ“œ Lyrics

Okunrin a fi abosile
Obirin rajo apada bo
Egbe eni arojo gbogbo
Se ni won fabo sile o
Ori mi jowo edami jowo
Bimo ba rajo tojo terun
Abo mi ko dara
Aseda to da aiye
o da oun gbogbo sile aiye
O wa da eniyan lawo ran ara re
Ofi wa joba lori won
Oda wa sile aiye lati wa joro
Oun gbogbo to da
Aiye lofi se oja
Se wa ri orun nile wa
Aaah aiye wa dabi oja
Tami na laye
Tolukuluku naja re ti yo fi
pada sile eni lowunro
ase owunro
eni losan koni Dale
Oloja ale Ana tire
Gbogbo eniyan ni yo rele
Sugbon boti wu koja pe to
Keni to naja pe to
Eda amaje a gbagbe rara
Ile labo isinmi oko

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings