Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Oluwa Ari Ise Yin

👤 Db Comic 🎼 Oluwa Ari Ise Yin ⏱️ 3:31
🎵 1920 characters
⏱️ 3:31 duration
🆔 ID: 11149989

📜 Lyrics

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń rọwọ yín oo
Olúwa a ma ń ríṣẹ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

O máa ma ṣé elédùmarè
O máa ma ṣé o alátìlẹyìn
Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí
O máa ma ṣé o elédùmarè
O máa dúpẹ' dúpẹ' dúpẹ' alátìlẹyìn
Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
Tó dúró tì mí lẹ'yìn
Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí
Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
Tó dúró tì mí lẹ'yìn
Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí

Eeee eeee eeeeeee

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Gbogbo àwọn tátí rán lọ'wọ' tán ṣe bí Ọlọ'run kò wá tán bí
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Gbogbo àwọn tọ' ti rò wá pín tán ṣe bi Ọlọ'run kò wá tán bí
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Eẹẹẹẹẹ
Ibi ẹ fojú sí ọ'nà o gbà bẹ
Mọ tí lọ mọ' yín lọ'wọ' oooo
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ

Ẹhn ẹhn ẹhnẹhn

⏱️ Synced Lyrics

[00:12.14] Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
[00:16.80] Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
[00:21.04] Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[00:25.52] Olúwa a ma ń rọwọ yín oo
[00:30.77] Olúwa a ma ń ríṣẹ yìn oo
[00:34.92] Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[00:40.43] O máa ma ṣé elédùmarè
[00:44.32] O máa ma ṣé o alátìlẹyìn
[00:49.03] Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí
[00:53.51] O máa ma ṣé o elédùmarè
[00:59.14] O máa dúpẹ' dúpẹ' dúpẹ' alátìlẹyìn
[01:02.78] Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí
[01:07.81] Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
[01:12.88] Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
[01:16.78] Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[01:21.15] Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
[01:26.74] Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
[01:30.39] Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[01:48.54] Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
[01:50.91] Tó dúró tì mí lẹ'yìn
[01:53.39] Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí
[01:57.35] Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù
[02:00.42] Tó dúró tì mí lẹ'yìn
[02:02.52] Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí
[02:06.84] Eeee eeee eeeeeee
[02:08.08] Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
[02:11.84] Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
[02:15.38] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[02:19.54] Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo
[02:24.64] Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo
[02:29.50] Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[02:33.70] Gbogbo àwọn tátí rán lọ'wọ' tán ṣe bí Ọlọ'run kò wá tán bí
[02:38.85] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[02:42.84] Gbogbo àwọn tọ' ti rò wá pín tán ṣe bi Ọlọ'run kò wá tán bí
[02:48.11] Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[02:51.53] Eẹẹẹẹẹ
[02:52.56] Ibi ẹ fojú sí ọ'nà o gbà bẹ
[02:55.35] Mọ tí lọ mọ' yín lọ'wọ' oooo
[02:57.15] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[03:00.80] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[03:06.56] Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[03:10.50] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[03:15.39] Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ
[03:19.26] Ẹhn ẹhn ẹhnẹhn
[03:29.38]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings