Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Igbagbo

๐Ÿ‘ค Sola Allyson โ€ข ๐ŸŽผ Imuse! โ€ข โฑ๏ธ 4:18
๐ŸŽต 1495 characters
โฑ๏ธ 4:18 duration
๐Ÿ†” ID: 11592525

๐Ÿ“œ Lyrics

Igba miran o ma n se mi bii ki n pada seyin
Igba miran o ma n se mi bii ki n jowo Re
Igba ti 'ji aye ba n ja, bii ki n pada seyin
Igba t'okan mi poruru, bii ki n jowo Re
Sugbon mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
Sugbon mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo

Igbagbo mi duro lori ododo Re
Iwo lapata ayeraye, ibi isadi mi
B'okan mi poruru, ko le p'ase Re da lailai
Iwo s'olododo, mo si mo O ni Alaanu
Igbagbo mi ro mo O, Iwo ni agbara mi
Oke ni mo f'okan si, ibi ti iranwo gbe wa

Fun mi lokun atoke wa, ki n mase pada seyin
Ki n ma sise ninu iriri, ki n mase jowo Re
Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo

Iriri aye a maa fe so 'yan d'eni o ni 'gbagbo
Sibe mi o gbeke l'ohun kan leyin agbara Re
Ogbon ori eeyan o le roo ja, eto too ni lailai
Koda b'okan mi se 'yemeji, ileri too se o duro
Abrahamu, Serah, won rerin looto ntori o dabi pe yeye ni
Sibe won d'eni itokasi fun ibukun pipe

Fun mi lokun atoke wa, Iwo ni Alatileyin
Ki n ma subu, ki n la ajo yi ja, ki n mase jowo Re
Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
Mo mo daju Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:02.35] Igba miran o ma n se mi bii ki n pada seyin
[00:07.38] Igba miran o ma n se mi bii ki n jowo Re
[00:14.03] Igba ti 'ji aye ba n ja, bii ki n pada seyin
[00:20.66] Igba t'okan mi poruru, bii ki n jowo Re
[00:27.95] Sugbon mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[00:33.89] Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
[00:41.12] Sugbon mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[00:47.96] Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
[00:56.07] Igbagbo mi duro lori ododo Re
[01:03.05] Iwo lapata ayeraye, ibi isadi mi
[01:08.66] B'okan mi poruru, ko le p'ase Re da lailai
[01:15.20] Iwo s'olododo, mo si mo O ni Alaanu
[01:22.17] Igbagbo mi ro mo O, Iwo ni agbara mi
[01:28.13] Oke ni mo f'okan si, ibi ti iranwo gbe wa
[01:38.50] Fun mi lokun atoke wa, ki n mase pada seyin
[01:47.77] Ki n ma sise ninu iriri, ki n mase jowo Re
[01:55.35] Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[02:01.12] Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
[02:08.30] Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[02:14.95] Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
[02:23.31] Iriri aye a maa fe so 'yan d'eni o ni 'gbagbo
[02:30.07] Sibe mi o gbeke l'ohun kan leyin agbara Re
[02:36.51] Ogbon ori eeyan o le roo ja, eto too ni lailai
[02:42.87] Koda b'okan mi se 'yemeji, ileri too se o duro
[02:48.98] Abrahamu, Serah, won rerin looto ntori o dabi pe yeye ni
[02:55.79] Sibe won d'eni itokasi fun ibukun pipe
[03:06.57] Fun mi lokun atoke wa, Iwo ni Alatileyin
[03:13.90] Ki n ma subu, ki n la ajo yi ja, ki n mase jowo Re
[03:20.13] Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[03:26.71] Bee ni mo mo, Iwo ni Eni to s'olododo
[03:34.51] Tori mo gba, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[03:41.08] Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
[03:48.20] Mo mo daju Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[03:55.25] Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
[04:01.35] Tori mo mo, Iwo ni Eni ti kii ko ni sile
[04:08.95] Bee ni mo gba, Iwo ni Eni to s'olododo
[04:17.25]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings