Alujanjankijan
๐ต 1586 characters
โฑ๏ธ 3:44 duration
๐ ID: 11592571
๐ Lyrics
Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
E ma f'omo s'ile fun'ya je- Alujanjankijan
Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo- Alujanjankijan
(VERSE 1- Sola Allyson)
Ba mi n'omo mi, o ye k'o de'nu olomo
Oju merin lo n bi'mo, sugbon, igba oju li n w'omo
Omo t'a o ko, a gbe'le t'a ko ta
Omo t'a o to, a k'eso t'a ni ta
Omo n'igbeyin, omo l'ola, omo l'ola, omo n'iyi, omo l'ade
Omo l'ewa, omo l'eso oh ohhh
O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san
Igboya at'adura ni o gba- yi o da ahhh
(Sola Allyson- CHORUS)

Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan
(VERSE 2- Adekunle Gold)
Ori fun wa l'omo're bi i ti Samuel oh
Won ko Samu, o gb'eko oh, o si se'hun rere
If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know?
Train them with the love of God; abegi oh
Tori, alaigboran omo- asa ni
Agba o kunwo l'oju- asa ni
Agba o jo won l'oju oh- asa ni
Agba iya ni o da- asa ni
Alalugboran omo oh- omo ni
Won le d'eyan l'ola- omo ni
T'a ba to won daada o- omo ni
Won le d'eyan l'ola
(Adekunle Gold- CHORUS)
Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan

Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo oh- Alujanjankijan
E ma f'omo s'ile fun'ya je oh- Alujanjankijan
(CHORUS- Sola Allyson)
Iya, Iya ta'kun wa'le oh ohh- Alujanjankijan
E ma f'omo s'ile fun'ya je ohh- Alujanjankijan
Eni t'o bi'mo e lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan
Iya, baba, t'akun wa'le- Alujanjankijan

โฑ๏ธ Synced Lyrics
[00:08.96] Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
[00:13.29] Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
[00:17.87] E ma f'omo s'ile fun'ya je- Alujanjankijan
[00:22.19] Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo- Alujanjankijan
[00:27.54] (VERSE 1- Sola Allyson)
[00:28.40] Ba mi n'omo mi, o ye k'o de'nu olomo
[00:32.32] Oju merin lo n bi'mo, sugbon, igba oju li n w'omo
[00:36.59] Omo t'a o ko, a gbe'le t'a ko ta
[00:41.21] Omo t'a o to, a k'eso t'a ni ta
[00:45.22] Omo n'igbeyin, omo l'ola, omo l'ola, omo n'iyi, omo l'ade
[00:50.60] Omo l'ewa, omo l'eso oh ohhh
[00:54.33] O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san
[00:59.25] Igboya at'adura ni o gba- yi o da ahhh
[01:02.60] (Sola Allyson- CHORUS)
[01:03.42] Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
[01:07.62] Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan
[01:12.15] E ma f'omo s'ile fun'ya je- Alujanjankijan
[01:16.12] Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan
[01:21.77] (VERSE 2- Adekunle Gold)
[01:22.70] Ori fun wa l'omo're bi i ti Samuel oh
[01:26.59] Won ko Samu, o gb'eko oh, o si se'hun rere
[01:30.85] If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know?
[01:35.48] Train them with the love of God; abegi oh
[01:39.59] Tori, alaigboran omo- asa ni
[01:42.45] Agba o kunwo l'oju- asa ni
[01:44.74] Agba o jo won l'oju oh- asa ni
[01:47.24] Agba iya ni o da- asa ni
[01:49.14] Alalugboran omo oh- omo ni
[01:51.44] Won le d'eyan l'ola- omo ni
[01:53.68] T'a ba to won daada o- omo ni
[01:56.04] Won le d'eyan l'ola
[01:57.31] (Adekunle Gold- CHORUS)
[01:58.07] Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan
[02:01.92] Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan
[02:06.42] Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo oh- Alujanjankijan
[02:10.94] E ma f'omo s'ile fun'ya je oh- Alujanjankijan
[02:15.26] (CHORUS- Sola Allyson)
[02:16.07] Iya, Iya ta'kun wa'le oh ohh- Alujanjankijan
[02:20.09] E ma f'omo s'ile fun'ya je ohh- Alujanjankijan
[02:24.28] Eni t'o bi'mo e lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan
[02:29.12] Iya, baba, t'akun wa'le- Alujanjankijan
[02:32.10]