Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Olorun Awon Omo Ogun Master

👤 Sola Allyson Obaniyi 🎼 Ope ⏱️ 5:27
🎵 2911 characters
⏱️ 5:27 duration
🆔 ID: 11593902

📜 Lyrics

Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọba tó f'amo mo wá
Ọba tó lẹ' mi wá
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun

Ọba t'ó f'amo mo wá
Ọba t'ó lẹ' mi wá o
Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún

Níbi tó lẹ'wá julo ni Ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o
Imọ'lẹ' láṣọ re
Ọlá lo fi ṣá'so bora

Níbi tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé ni'wo wá o
Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi

Ahhhhh Ahhhhh
Ìwọ lọ lèmi mi ò
Ìwọ lo nígbà mi

Ìṣẹ'lẹ' inú ìṣẹ̀dá nṣá'fihàn àgbàrá rẹ
Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o
Pẹ'lú ifilelẹ' tí ó lè Páráda láì láì
Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́n

Ṣe bí èyí tà ri là ń wi
Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye
Àìmọye làwọn tá kan n mo l'àrà
Ẹ'dá ó lè ṣá kàwé wọn

Ibí tó lẹ'wá julo ni ìwọ gbé
órí obiiri ayé ni'wo wá o
Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi
Ọba tó lẹ' mi mi
Ọba tó ní gbà mi

Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh
Ọba tó lẹ'mi mi
Ọba tó ní gbà mi

Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
Call: Àìmọye àwọn èyí tá' ó lé mọ' bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ'n bá ti ọgbọ'n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ' á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì
Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogun
Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní
Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

⏱️ Synced Lyrics

[00:18.52] Ògo ìyìn ọlá
[00:23.32] Lóye Ọlọ́run
[00:26.33] Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
[00:30.39] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[00:34.28] Ògo Ìyìn ọlá
[00:37.27] Lóye Ọlọ́run
[00:41.45] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[00:45.50] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[00:49.83] Ọba tó f'amo mo wá
[00:53.04] Ọba tó lẹ' mi wá
[00:57.16] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[01:01.39] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
[01:04.68] Ọba t'ó f'amo mo wá
[01:08.70] Ọba t'ó lẹ' mi wá o
[01:12.39] Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
[01:16.76] Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
[01:19.74] Níbi tó lẹ'wá julo ni Ìwọ gbé
[01:23.29] Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o
[01:27.59] Imọ'lẹ' láṣọ re
[01:31.63] Ọlá lo fi ṣá'so bora
[01:35.20] Níbi tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé
[01:39.06] Lórí obiiri ayé ni'wo wá o
[01:43.49] Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
[01:45.77] O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora
[01:50.89] Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
[01:54.54] Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
[01:58.60] Ọba tó lẹ' mi mi
[02:02.01] Ọba tó ní gbà mi
[02:06.39] Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
[02:09.42] Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
[02:13.43] Ọba tó lẹ' mi mi
[02:17.11] Ọba tó ní gbà mi
[02:23.53] Ahhhhh Ahhhhh
[02:29.85] Ìwọ lọ lèmi mi ò
[02:32.41] Ìwọ lo nígbà mi
[02:38.02] Ìṣẹ'lẹ' inú ìṣẹ̀dá nṣá'fihàn àgbàrá rẹ
[02:43.12] Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o
[02:47.25] Pẹ'lú ifilelẹ' tí ó lè Páráda láì láì
[02:51.22] Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́n
[02:54.96] Ṣe bí èyí tà ri là ń wi
[02:58.70] Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye
[03:02.49] Àìmọye làwọn tá kan n mo l'àrà
[03:06.45] Ẹ'dá ó lè ṣá kàwé wọn
[03:10.38] Ibí tó lẹ'wá julo ni ìwọ gbé
[03:13.89] órí obiiri ayé ni'wo wá o
[03:18.15] Imọ'lẹ' láṣọ rẹ
[03:21.24] O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora
[03:25.54] Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò
[03:29.44] Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi
[03:33.94] Ọba tó lẹ' mi mi
[03:37.78] Ọba tó ní gbà mi
[03:40.54] Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko
[03:44.61] Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh
[03:49.37] Ọba tó lẹ'mi mi
[03:52.72] Ọba tó ní gbà mi
[03:56.52] Ògo ìyìn ọlá
[04:01.34] Lóye Ọlọ́run
[04:04.86] Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
[04:09.27] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[04:12.19] Ògo Ìyìn ọlá
[04:16.98] Lóye Ọlọ́run
[04:20.32] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[04:23.92] Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[04:27.18] Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn
[04:31.78] Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[04:34.70] Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ
[04:39.80] Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
[04:42.36] Call: Àìmọye àwọn èyí tá' ó lé mọ' bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ
[04:47.63] Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[04:50.26] Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ'n bá ti ọgbọ'n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún
[04:54.92] Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
[04:58.05] Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ
[05:03.15] Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún
[05:06.18] Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ' á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì
[05:11.38] Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogun
[05:13.46] Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní
[05:18.28] Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
[05:22.17]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings