Mohbad - Sabi (Official Audio)
🎵 1812 characters
⏱️ 2:20 duration
🆔 ID: 12162708
📜 Lyrics
(No one is sleeker)
Wọn ni ki n wa baba to sabi
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn)
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn)
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Uh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun
Uh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun
Huh, ki lo de o jere o?
Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
Uh, wọn gun'yan mi kere o
Mo fíìmu wọn fọn fere o
Ninu aiye, mi o kere o
To ba de igboro, ko lọ béère o
Wọn ni ki n wa baba to sabi o

Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun o
Huh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyan Baba Fela ni, kẹ gba fun
Huh, ki lo de o jere o?
Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
Uh, wọn gun'yan mi kere o
Mo fíìmu wọn fọn fere o
Ninu aye, mi o kere
To ba de igboro, ko lọ béèrè o
I will exalt You, Lord
For You have lifted me up
Has not let my foes to rejoice over me
(Timi Jay on the track)

⏱️ Synced Lyrics
[00:07.03] (No one is sleeker)
[00:09.83] Wọn ni ki n wa baba to sabi
[00:12.45] Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi
[00:14.70] Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
[00:16.80] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[00:19.41] Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn)
[00:21.73] Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn)
[00:23.94] Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
[00:26.40] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[00:28.78] Uh, ọmọ ologo to sabi
[00:31.17] Ọmọ gbera tan, o b'omi si garri
[00:33.65] O wọ Yankee o, Atlanta per roof
[00:35.81] Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun
[00:38.23] Uh, ọmọ ologo to sabi
[00:40.64] Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
[00:43.06] O wọ Yankee o, Atlanta per roof
[00:45.49] Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun
[00:47.48] Huh, ki lo de o jere o?
[00:50.11] Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
[00:52.29] Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
[00:54.96] Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
[00:56.95] Uh, wọn gun'yan mi kere o
[01:00.19] Mo fíìmu wọn fọn fere o
[01:02.70] Ninu aiye, mi o kere o
[01:04.44] To ba de igboro, ko lọ béère o
[01:06.90] Wọn ni ki n wa baba to sabi o
[01:09.46] Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi
[01:11.99] Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
[01:13.87] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[01:16.49] Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn)
[01:18.75] Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn)
[01:21.11] Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
[01:23.32] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
[01:25.89] Uh, ọmọ ologo to sabi
[01:28.22] Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
[01:30.53] O wọ Yankee o, Atlanta per roof
[01:32.91] Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun o
[01:35.24] Huh, ọmọ ologo to sabi
[01:37.66] Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
[01:40.01] O wọ Yankee o, Atlanta per roof
[01:42.42] Èèyan Baba Fela ni, kẹ gba fun
[01:44.53] Huh, ki lo de o jere o?
[01:47.15] Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
[01:49.23] Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
[01:51.86] Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
[01:54.01] Uh, wọn gun'yan mi kere o
[01:57.30] Mo fíìmu wọn fọn fere o
[01:59.55] Ninu aye, mi o kere
[02:01.48] To ba de igboro, ko lọ béèrè o
[02:03.40] I will exalt You, Lord
[02:05.66] For You have lifted me up
[02:08.15] Has not let my foes to rejoice over me
[02:13.04] (Timi Jay on the track)
[02:15.54]