Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

OhEmGee Yoruba Hymns Medley 1

๐Ÿ‘ค EmmaOMG โ€ข ๐ŸŽผ Yoruba Hymns โ€ข โฑ๏ธ 11:01
๐ŸŽต 1541 characters
โฑ๏ธ 11:01 duration
๐Ÿ†” ID: 12230076

๐Ÿ“œ Lyrics

Oluwa orun ohun aye,
Wo niyi atope yefun
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Oruntiran atafefe, gbogbo eweko so tife Re, won lo nmu irugbin dara
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Fun ara lile wa gbogbo
Fun gbogbo ibukun aye
Awa yin O, asi dupe
Onibu

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Oko dunwa li omo Re
Ofi fun aye ese yi
Pelu Re lofe lohun fun wa lohun gbogbo

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

O fun wa li Emi Mimo Re
Emi Iye ati Agbara
Orojo ekun ibukun Re lewa lori

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Jesu! Fun idariji ese wa
Ati fun ireti Orun
Kilohun taba fifun O
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Owo ti ana ofo ni
Sugbon eyi tafi fun O, oje isura titi aye
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Ohun tabun O Oluwa
'Wo O san le pada fun wa
Layo laota O lore
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Ni odo Re lati san wa,Olorun Olodumare,
Jeka le ba O gbe titi
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Onibu ore
Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

Si O, Olutunu Orun, fun ore ati Agbara Re, anko alleluia

Si O, ife Eni towa ninu majemu Olorun
anko alleluia

Si O, agbara Eniti owe ni mo Totun wo nisan
anko alleluia

Si O, Oluko atore, Amona wa toju MI,
anko alleluia

Si O, eniti Kristi ran, Ade ohun gbogbo ebun Re
anko alleluia

We are singing unto the Lord
Singing alleluia

Onibu ore
Bawo laba tife O to
Onibu ore

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings