Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Awodi (Official Visualizer)

👤 Asake 🎼 Asake Videos ⏱️ 2:17
🎵 1621 characters
⏱️ 2:17 duration
🆔 ID: 13963955

📜 Lyrics

(Ọlọlade mi, Àṣàkẹ)
(Tune in to the king of sounds and blues)

Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà
Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder
I wonder, Americana wonder oo
Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?

Catfish lórí títí
Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
They wanna know what I'm thinking

Many, many things, I no fit ṣàlàyé o
2022, mó gbé wọn trabayé o
Olùwà ló gbé from the slum to the top
Èmí kọ, àwọn kọ, wọn o lé t'Ọlọrun
Ìṣù jọba lórí ìyàn
Kémí má ní ìjọba òṣìkà

Òjo l'ọkọ àgbàdo
As e dey go, jásí, my nigga
Aroma ńjo gẹ́, aroma ńle wọn
Aroma ńdé bẹ, fabẹ yá o
Mó ge wọn bí Babayaro
Akabi Kaola, óyà, kabi lórí àwá o

Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà
Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder ('der)
I wonder, Americana wonder oo
Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?

Catfish lórí títí
Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
They wanna know what I'm thinking

They wanna know (aroma re o)
They wanna know (aroma re o)
Aroma ńjo gẹ, aroma ńle wọn
Aroma ńde bẹ fàbẹ yá o
Mó ge wọn bí Babayaro
Akabi Kaola, ó yà, kabi lórí àwá o

⏱️ Synced Lyrics

[00:05.35] (Ọlọlade mi, Àṣàkẹ)
[00:07.93]
[00:14.65] (Tune in to the king of sounds and blues)
[00:17.78] Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà
[00:22.67] Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
[00:26.26] Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder
[00:31.17] I wonder, Americana wonder oo
[00:34.46] Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?
[00:38.12] Catfish lórí títí
[00:39.41] Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
[00:42.45] Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
[00:46.14] My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
[00:49.18] They wanna know what I'm thinking
[00:51.75] Many, many things, I no fit ṣàlàyé o
[00:55.99] 2022, mó gbé wọn trabayé o
[01:00.22] Olùwà ló gbé from the slum to the top
[01:03.78] Èmí kọ, àwọn kọ, wọn o lé t'Ọlọrun
[01:08.03] Ìṣù jọba lórí ìyàn
[01:09.88] Kémí má ní ìjọba òṣìkà
[01:12.05] Òjo l'ọkọ àgbàdo
[01:13.63] As e dey go, jásí, my nigga
[01:16.17] Aroma ńjo gẹ́, aroma ńle wọn
[01:18.47] Aroma ńdé bẹ, fabẹ yá o
[01:20.45] Mó ge wọn bí Babayaro
[01:21.86] Akabi Kaola, óyà, kabi lórí àwá o
[01:25.06] Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà
[01:29.95] Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
[01:33.56] Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder ('der)
[01:38.42] I wonder, Americana wonder oo
[01:41.79] Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?
[01:45.33] Catfish lórí títí
[01:46.75] Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
[01:49.74] Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
[01:53.58] My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
[01:56.33] They wanna know what I'm thinking
[01:59.32] They wanna know (aroma re o)
[02:03.64] They wanna know (aroma re o)
[02:06.80] Aroma ńjo gẹ, aroma ńle wọn
[02:08.88] Aroma ńde bẹ fàbẹ yá o
[02:11.07] Mó ge wọn bí Babayaro
[02:12.32] Akabi Kaola, ó yà, kabi lórí àwá o
[02:13.38]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings