Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Olodumare

๐Ÿ‘ค Eezee Global โ€ข ๐ŸŽผ Olodumare โ€ข โฑ๏ธ 3:10
๐ŸŽต 983 characters
โฑ๏ธ 3:10 duration
๐Ÿ†” ID: 16166707

๐Ÿ“œ Lyrics

Atabatubu Olodumare Oba mimo
Oba mi olola
Oba mi ologo
Oba imole
Kabiyesi Olodumare
Eni to d'aye at'orun
To dami laworan re
Abiyamo ode orun

Atabatubu Olodumare Oba pipe
Oba to momi, Oba to moomi
Omi imi e simi
Sebi iwo lo ni kin maa mi
Lo ni kin maa yo
Lo ni kin maa yonfanda o
Ninu ogo gangan lo tin fohun
Ninu ola nlanla lo tin sise
Ah n o yin o logo
N o se o loba
N o sa ferire re
Oba mi olola
Oba mi olola

Ti Baba lase o, ti Baba loye
Ti Baba lase o, ti Baba loye
Ni ghohungbohun oro re
Emi mimo bale mi
Ara mi si ya gaga
Ti Baba lase

I lean on
Oro ti n gbenu omo eda sise
On your word
Eyi ti n gbenu omo eda d'ogo
On your word oh God
Olodumare, Oba akoda, Oba aseda
On your word oh God
T'o ba ti n s'oro be naa ni o

Ti Baba lase o, ti Baba loye (I lean on)
Ti Baba lase o, ti Baba loye (On your word)
Ni gbohungbohun oro re (On your word oh God)
Emi mimo bale mi
Ara mi si ya gaga (On your word oh God)
Ti Baba lase

Oremi atata
Baba Alailenikan
Eni to femi o
K'aye to momi

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:09.13] Atabatubu Olodumare Oba mimo
[00:17.46] Oba mi olola
[00:20.01] Oba mi ologo
[00:22.29] Oba imole
[00:26.75] Kabiyesi Olodumare
[00:30.88] Eni to d'aye at'orun
[00:34.99] To dami laworan re
[00:39.15] Abiyamo ode orun
[00:43.54] Atabatubu Olodumare Oba pipe
[00:51.54] Oba to momi, Oba to moomi
[00:55.94] Omi imi e simi
[00:58.74] Sebi iwo lo ni kin maa mi
[01:02.78] Lo ni kin maa yo
[01:04.54] Lo ni kin maa yonfanda o
[01:08.61] Ninu ogo gangan lo tin fohun
[01:12.97] Ninu ola nlanla lo tin sise
[01:16.83] Ah n o yin o logo
[01:19.73] N o se o loba
[01:21.54] N o sa ferire re
[01:23.96] Oba mi olola
[01:28.47] Oba mi olola
[01:34.09] Ti Baba lase o, ti Baba loye
[01:40.08] Ti Baba lase o, ti Baba loye
[01:45.42] Ni ghohungbohun oro re
[01:48.52] Emi mimo bale mi
[01:51.38] Ara mi si ya gaga
[01:55.18] Ti Baba lase
[01:57.90] I lean on
[02:01.50] Oro ti n gbenu omo eda sise
[02:04.26] On your word
[02:07.83] Eyi ti n gbenu omo eda d'ogo
[02:10.16] On your word oh God
[02:13.02] Olodumare, Oba akoda, Oba aseda
[02:15.85] On your word oh God
[02:17.55] T'o ba ti n s'oro be naa ni o
[02:24.08] Ti Baba lase o, ti Baba loye (I lean on)
[02:29.27] Ti Baba lase o, ti Baba loye (On your word)
[02:34.56] Ni gbohungbohun oro re (On your word oh God)
[02:38.07] Emi mimo bale mi
[02:40.97] Ara mi si ya gaga (On your word oh God)
[02:44.42] Ti Baba lase
[02:48.31] Oremi atata
[02:53.45] Baba Alailenikan
[02:57.94] Eni to femi o
[03:00.78] K'aye to momi
[03:05.95]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings