Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Feel Good (Audio) | val9ja.com

👤 Mohbad 🎼 @val9ja_com ⏱️ 2:50
🎵 1454 characters
⏱️ 2:50 duration
🆔 ID: 17204808

📜 Lyrics

(Niphkeys, Niphkeys)

Imọlẹ
Plenty enemy (Mohbad)
Wey dey follow me
Ma jẹ k'ọn mu mi
Even if na dying minute

Emi ọmọ ghetto
Mo ti d'aji lo motor (mo ti d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)

Emi ti gbera (on God)
Lati 4:30 (on God)
Wọn le, wọn ba ti (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (on God)
I drip on check, o tu wa on point
Imọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)

Ahn, when I dey Ikorodu, sapa mu mi
Mo ma ronu
Mo ma sunkun (mo ma sunkun)
Ehn, I don work tire
I don pray tire
I don go Mountain of Fire, ah

I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I'll party away
I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I smoke it away
I feel good, pa, ran-ran, pa, ran-ran
Ọmọ iya mi, ma lọ ronu o, ko pa, ran-ran, pa, ran-ran
I feel good (pa, ran-ran)

Emi ọmọ ghetto (emi ọmọ ghetto)
Mo ti d'aji lo motor (mo ma ti d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)

Emi ti gbera (on God)
Lati 4:30 (on God)
Wọn le, wọn ba ti (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (wọn mu, wọn filẹ) (on God)
I drip on check, o tu wa on point
Imọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)

Imọlẹ, o wa'lẹ
Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
Lat'aye tipẹ-tipẹ
Imọlẹ, o wa'lẹ
Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
Lát'aye tipẹ-tipẹ

Plenty enemy
Wey dey follow me
Ma jẹ k'ọn mu mi
(Imọlẹ)
(Timi Jay on the track)

⏱️ Synced Lyrics

[00:00.00] (Niphkeys, Niphkeys)
[00:05.50] Imọlẹ
[00:07.76] Plenty enemy (Mohbad)
[00:11.73] Wey dey follow me
[00:15.86] Ma jẹ k'ọn mu mi
[00:19.42] Even if na dying minute
[00:23.85] Emi ọmọ ghetto
[00:27.75] Mo ti d'aji lo motor (mo ti d'aji lo motor)
[00:31.78] My grace na auto, automatic
[00:35.67] Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)
[00:39.76] Emi ti gbera (on God)
[00:41.67] Lati 4:30 (on God)
[00:43.66] Wọn le, wọn ba ti (on God)
[00:45.72] Wọn mu, wọn filẹ (on God)
[00:47.51] I drip on check, o tu wa on point
[00:50.05] Imọlẹ (on God)
[00:52.24] O wa'lẹ (on God)
[00:54.88] (On God)
[00:56.15] Ahn, when I dey Ikorodu, sapa mu mi
[00:58.69] Mo ma ronu
[01:00.62] Mo ma sunkun (mo ma sunkun)
[01:04.48] Ehn, I don work tire
[01:06.63] I don pray tire
[01:08.29] I don go Mountain of Fire, ah
[01:12.95] I know there is a day
[01:14.83] All my pains will go away
[01:17.07] 'Til then, I'll party away
[01:21.17] I know there is a day
[01:23.15] All my pains will go away
[01:25.36] 'Til then, I smoke it away
[01:28.76] I feel good, pa, ran-ran, pa, ran-ran
[01:32.15] Ọmọ iya mi, ma lọ ronu o, ko pa, ran-ran, pa, ran-ran
[01:36.86] I feel good (pa, ran-ran)
[01:39.02] Emi ọmọ ghetto (emi ọmọ ghetto)
[01:42.89] Mo ti d'aji lo motor (mo ma ti d'aji lo motor)
[01:47.03] My grace na auto, automatic
[01:50.85] Wọn fẹ ba mi ya photo (photo)
[01:54.94] Emi ti gbera (on God)
[01:56.98] Lati 4:30 (on God)
[01:58.83] Wọn le, wọn ba ti (on God)
[02:01.02] Wọn mu, wọn filẹ (wọn mu, wọn filẹ) (on God)
[02:02.94] I drip on check, o tu wa on point
[02:05.40] Imọlẹ (on God)
[02:07.38] O wa'lẹ (on God)
[02:10.07] (On God)
[02:12.02] Imọlẹ, o wa'lẹ
[02:14.24] Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
[02:16.12] Lat'aye tipẹ-tipẹ
[02:20.42] Imọlẹ, o wa'lẹ
[02:22.29] Bo ṣe n mulẹ, lọ ṣe n jẹ
[02:24.31] Lát'aye tipẹ-tipẹ
[02:28.03] Plenty enemy
[02:32.18] Wey dey follow me
[02:36.25] Ma jẹ k'ọn mu mi
[02:37.92] (Imọlẹ)
[02:40.63] (Timi Jay on the track)
[02:40.91]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings