Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Oja

👤 TeeFamous 🎼 Oja ⏱️ 2:12
🎵 2039 characters
⏱️ 2:12 duration
🆔 ID: 17525502

📜 Lyrics

(ExtraPro)
Ọmọ Iya 'Dewale oh

I getti one kele (kele), t'omán kpin kári'lè (r'ilè)
L'obá wámi wá'lè (wá'lè), ajè, na fine kele (kele)
O l'òhun fóh fun áye, pè "potamoshe" ('moshe)
Èrè mèlo l'áti shèè? (L'áti shèè), òwò njòna, ájá n sááre ('ja n sááre)
Ájá n sááre, òwò njòna (òwò njòna)
Aunty Rose, ẹ wanbi na (wanbi na)
Kilẹn ṣhasi na? (Ṣhasi na)
She said "cana dey turn me on" (turn me on)

After one-two puff, aunty ti bọṣhọ
Ẹwá w'òrè gele (obi), pe-pe-renpe (obi)
Ngozi kọlá (obi), ẹ rọra mu ọmu
Èmi mo wè, iwọ l'ofá
O jẹ rọra gbè (rọra gbè), rọra fá (rọra fa)
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè nfá cana, kọ lọn gbẹnu si baba
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè gbẹnusi cana, kọ lọn gbẹnu si baba

My brother, see, dem no dey force person to dey smoke igbo (smoke igbo)
For person wey dey kpo, you no need to tell ma "o tito" (o tito)
If you choke you, boy, e go dove (e go dove)
Fa-faside dey clock, you go know (you go know)
But I swear, my brother, see some strange dey past toto (toto)
I just dey wonder, why t'ònigbo sóh fun mi pè, mo wọ'mọ tó wèh (sóh fun mi pè, mo wọ'mọ tó wèh)

Ọsàn igbo (igbo), álẹ igbo (igbo)
Kilẹtomọ, á tuntun-ji mu'gbo (igbo)
Popo tidè, kò yá fẹlu 'gbo
Ọmọ timo gbèwa, ko ṣájumi fò
Uh-uh-uh, aṣhè ghetto ni mo gbè

Èmi mo wè, iwọ l'ofá (ṣuuuuuu-ahh)
O jẹ rọra gbè (rọra gbè), rọra fá (rọra fa)
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè nfá cana, kọ lọn gbẹnu si baba
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè gbẹnusi cana, kọ lọn gbẹnu si baba

Èmi mo wè, iwọ l'ofá
O jẹ rọra gbè (rọra gbè), rọra fá (rọra fa)
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè nfá cana, kọ lọn gbẹnu si baba
B'oshèè nfá Backii, kọ lọn fá brown rizla
B'oshèè gbẹnusi cana, kọ lọn gbẹnu si baba

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings