Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Wonder

👤 Barry Jhay 🎼 Barry Back 2 ⏱️ 2:36
🎵 1503 characters
⏱️ 2:36 duration
🆔 ID: 20431791

📜 Lyrics

(Yo-)
Yeah

Take it or not, I'm blessed
Ṣẹ gbọ o? Oh, yes
And no son of man can take my joy away
Wetin be my own no go pass me by
Ẹkùn ati òṣì, bye-bye
Tẹ ba ro pe ẹ n ṣe mi Atanda
Ara yin lẹ n ṣe

Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
The horror mọ wọn lọwọ
K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
Ni mo fi sun ṣòkòtò
Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
And e no get where e touch (aje, aje)

Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
Kiamọsa ni ko tete
Ma tori mi lọ jẹ gbese
Anoti, anoti, allele
Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
Psycho pọ lode

Àwọn le mọ le ṣe
Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o
Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
Ara rẹ loo pa
Itakun to ni kerin ma wọ'dò, to ni kerin ma wọ'dò
Toun terin ni wọn jọ lọ (ayan o)

Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
The horror mọ wọn lọwọ
K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
Ni mo fi sun ṣòkòtò
Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
And e no get where e touch (aje, aje)

Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
Kiamọsa ni ko tete
Ma tori mi lọ jẹ gbese
Anoti, anoti, allele
Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
Psycho pọ lode
Àwọn le mọ le ṣe
Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o

Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
Ara rẹ loo pa
Itakun to ni kerin ma wọ'dò, o ni kerin ma wọ'dò
Toun terin ni wọn jọ lọ (Yo Dips)

⏱️ Synced Lyrics

[00:15.05] (Yo-)
[00:16.16] Yeah
[00:18.10] Take it or not, I'm blessed
[00:21.07] Ṣẹ gbọ o? Oh, yes
[00:22.63] And no son of man can take my joy away
[00:26.10] Wetin be my own no go pass me by
[00:28.67] Ẹkùn ati òṣì, bye-bye
[00:31.05] Tẹ ba ro pe ẹ n ṣe mi Atanda
[00:33.22] Ara yin lẹ n ṣe
[00:35.00] Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
[00:37.25] The horror mọ wọn lọwọ
[00:38.81] K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
[00:41.07] Ni mo fi sun ṣòkòtò
[00:42.91] Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
[00:45.16] And e no get where e touch (aje, aje)
[00:47.28] Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
[00:49.49] Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
[00:51.37] Kiamọsa ni ko tete
[00:53.50] Ma tori mi lọ jẹ gbese
[00:55.13] Anoti, anoti, allele
[00:56.71] Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
[00:58.91] Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
[01:01.68] Psycho pọ lode
[01:03.80] Àwọn le mọ le ṣe
[01:05.15] Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o
[01:07.65] Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
[01:13.25] Ara rẹ loo pa
[01:15.25] Itakun to ni kerin ma wọ'dò, to ni kerin ma wọ'dò
[01:20.58] Toun terin ni wọn jọ lọ (ayan o)
[01:24.32] Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
[01:26.22] The horror mọ wọn lọwọ
[01:28.23] K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?"
[01:30.48] Ni mo fi sun ṣòkòtò
[01:32.33] Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ
[01:34.50] And e no get where e touch (aje, aje)
[01:36.62] Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
[01:38.53] Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
[01:40.48] Kiamọsa ni ko tete
[01:42.67] Ma tori mi lọ jẹ gbese
[01:44.35] Anoti, anoti, allele
[01:46.09] Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
[01:48.13] Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè
[01:50.97] Psycho pọ lode
[01:53.16] Àwọn le mọ le ṣe
[01:54.45] Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o
[01:57.03] Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila
[02:02.45] Ara rẹ loo pa
[02:04.34] Itakun to ni kerin ma wọ'dò, o ni kerin ma wọ'dò
[02:09.21] Toun terin ni wọn jọ lọ (Yo Dips)
[02:15.16]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings