Jesu Jowo (The Benediction)
🎵 1361 characters
⏱️ 5:43 duration
🆔 ID: 24047953
📜 Lyrics
Je ki ore ofe Baba
Ati ti Omo
Ati ti
(Emi Mimo)
Ko bale wa
Ko gbe wa ga
Ko sin wa lo
Ko se oju Re ko mo’le si wa lara
(Oju Olorun ko wa l’ara wa)
Babaaa
(Babaaa)
Who art in Heaven
Hallowed be your name
(Ooooh titi lai)
(Jagun jagun ode Orun
Alaafin ode Orun)
Olowo gbogboro ti nyo’mo Re l’ofin aiye
Gba wa O
Owo otun Oluwa
T’o nse agbara
Ko ro yin l’agbara
Owo otun Oluwa
T’o nse abo
Ko dabobo yin
Owo otun Oluwa
T’o nse ibukun
Ninu ara, ati ninu Emi, ko 'bukun fun yin
Jesu jowo
Jesu jowo
(Wiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
Jowo
Jesu jowo
(Jowo Jowo Jowo)
Ma je k’a lo lofo
Jowo Jowo
(Wiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
Jowo
(Jesu Jowo)
Hmmm
(Gbo adura wa)
Jowo Jowo
(Wiiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
As we go through each door, Jesu ba wa lo (Ase)
Aye ibanuje, Oluwa ti’lekun mo
Aye orire, idunnu, letter ayo
Oluwa si sile fun wa
Gbogbo eyi a toro
Oluwa fi le wa l’owo
Please, Please, Please! (Ase)
T’ori wa bere ohun rere (Ase)
K’a ri ba ti se (Ase)
K’a r’ona gbe gba (Ase)
Kristi Alase l’aiye l’Orun (Ase)
Awon to wa ni dubule aisan
K’o ri iwosan (Ase)
K’o ri iwosan (Ase)
Afefe itura (Ase)
Ko fe si won (Ase)
Gbe won dide (Ase)
Iye ko je ti won (Ase)
Ago ara won ba won tun se (Ase)
F’eje Jesu (Ase)
We wa mo (Ase)
Ase (Ase)
Alafia ko je ti gbogbo wa (Ase)
Ase mbe l’odo Re (Ase)
F’ase si (Ase)
F’ase dahun (Ase)
Ati ti Omo
Ati ti
(Emi Mimo)
Ko bale wa
Ko gbe wa ga
Ko sin wa lo
Ko se oju Re ko mo’le si wa lara
(Oju Olorun ko wa l’ara wa)
Babaaa
(Babaaa)
Who art in Heaven
Hallowed be your name
(Ooooh titi lai)
(Jagun jagun ode Orun
Alaafin ode Orun)
Olowo gbogboro ti nyo’mo Re l’ofin aiye
Gba wa O
Owo otun Oluwa
T’o nse agbara
Ko ro yin l’agbara
Owo otun Oluwa
T’o nse abo
Ko dabobo yin
Owo otun Oluwa
T’o nse ibukun
Ninu ara, ati ninu Emi, ko 'bukun fun yin
Jesu jowo
Jesu jowo
(Wiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
Jowo
Jesu jowo
(Jowo Jowo Jowo)
Ma je k’a lo lofo
Jowo Jowo
(Wiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
Jowo
(Jesu Jowo)
Hmmm
(Gbo adura wa)
Jowo Jowo
(Wiiwi nti wa, ase mbe l’odo Re)
As we go through each door, Jesu ba wa lo (Ase)
Aye ibanuje, Oluwa ti’lekun mo
Aye orire, idunnu, letter ayo
Oluwa si sile fun wa
Gbogbo eyi a toro
Oluwa fi le wa l’owo
Please, Please, Please! (Ase)
T’ori wa bere ohun rere (Ase)
K’a ri ba ti se (Ase)
K’a r’ona gbe gba (Ase)
Kristi Alase l’aiye l’Orun (Ase)
Awon to wa ni dubule aisan
K’o ri iwosan (Ase)
K’o ri iwosan (Ase)
Afefe itura (Ase)
Ko fe si won (Ase)
Gbe won dide (Ase)
Iye ko je ti won (Ase)
Ago ara won ba won tun se (Ase)
F’eje Jesu (Ase)
We wa mo (Ase)
Ase (Ase)
Alafia ko je ti gbogbo wa (Ase)
Ase mbe l’odo Re (Ase)
F’ase si (Ase)
F’ase dahun (Ase)