Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Je'le O Sinmi

👤 Brymo 🎼 Tabula Rasa ⏱️ 3:58
🎵 1507 characters
⏱️ 3:58 duration
🆔 ID: 24320748

📜 Lyrics

Ní kékeré, a má ńṣeré
À mà ń f'àwọn àgbààgbà ṣeré
À má ńmere
Ìyá Dele, sọ fún Dele
Kò ye fó 'na, kò tó wo 'na, ko to mere

Bọ 'mọdé ńṣeré, kò tó ṣeré délé
Àwọn àgbà-gbà wọn mà ṣé'to were-were
Bọ 'mọdé ńṣíṣẹ, ko tó rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k'ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ' jèrè
Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were

A mà ń ṣeré
À mà ń sáré
À mà ńṣubú, à mà ń dídé, a mà ńdele
Ìyá Taye sọ fún Taye
Kò yé sọrọ, kò to mọ'rọ yeke-yeke

K'ọmọ o to sa ńlé
Ko tó dí pé o ń sáré kírì
Àwọn àgbà-gbà wọn má ṣètò were-were
B'ọmọdé ń ṣíṣẹ, ah, ko to rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k'ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ' jèrè
Jẹ lé o sinmi o, o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were (were-were)

Wure, wure, wure e-

Jẹ lé o sinmi (jẹ lé o sinmi)
Ko sinmi (ko sinmi)
K'ọmọdé o kàwé (k'ọmọdé o kàwé)
Kò jèrè (kò jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were

Ko sinmi (ko sinmi)
Ani, ko sinmi (ani, ko sinmi)
Ko kà'we (ko kà'we)
Ko jèrè (ko jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Ko, ko sinmi, ko-ko jèrè

⏱️ Synced Lyrics

[00:32.21] Ní kékeré, a má ńṣeré
[00:36.52] À mà ń f'àwọn àgbààgbà ṣeré
[00:38.71] À má ńmere
[00:40.93] Ìyá Dele, sọ fún Dele
[00:45.25] Kò ye fó 'na, kò tó wo 'na, ko to mere
[00:49.50] Bọ 'mọdé ńṣeré, kò tó ṣeré délé
[00:53.92] Àwọn àgbà-gbà wọn mà ṣé'to were-were
[00:58.02] Bọ 'mọdé ńṣíṣẹ, ko tó rí jẹ
[01:02.95] Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ
[01:06.92] Jẹ lé o sinmi ooo
[01:09.26] Jẹ lé o sinmi
[01:11.00] Jẹ k'ọmọdé o kàwé
[01:13.59] Kò kẹ'kọ' jèrè
[01:15.65] Jẹ lé o sinmi ooo
[01:18.08] Jẹ lé o sinmi
[01:20.19] Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were
[01:24.45] A mà ń ṣeré
[01:26.84] À mà ń sáré
[01:28.94] À mà ńṣubú, à mà ń dídé, a mà ńdele
[01:33.34] Ìyá Taye sọ fún Taye
[01:37.64] Kò yé sọrọ, kò to mọ'rọ yeke-yeke
[01:41.98] K'ọmọ o to sa ńlé
[01:43.84] Ko tó dí pé o ń sáré kírì
[01:46.41] Àwọn àgbà-gbà wọn má ṣètò were-were
[01:50.57] B'ọmọdé ń ṣíṣẹ, ah, ko to rí jẹ
[01:55.22] Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ
[01:59.53] Jẹ lé o sinmi ooo
[02:01.65] Jẹ lé o sinmi
[02:03.57] Jẹ k'ọmọdé o kàwé
[02:05.87] Kò kẹ'kọ' jèrè
[02:08.30] Jẹ lé o sinmi o, o sinmi
[02:12.49] Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were (were-were)
[02:18.04]
[02:24.22] Wure, wure, wure e-
[02:27.19]
[02:34.42] Jẹ lé o sinmi (jẹ lé o sinmi)
[02:36.89] Ko sinmi (ko sinmi)
[02:38.59] K'ọmọdé o kàwé (k'ọmọdé o kàwé)
[02:41.21] Kò jèrè (kò jèrè)
[02:43.10] Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
[02:45.67] Ko sinmi (ko sinmi)
[02:47.44] Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were
[02:52.06] Ko sinmi (ko sinmi)
[02:53.73] Ani, ko sinmi (ani, ko sinmi)
[02:56.65] Ko kà'we (ko kà'we)
[02:58.75] Ko jèrè (ko jèrè)
[03:00.69] Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
[03:03.17] Ko sinmi (ko sinmi)
[03:04.76] Ko, ko sinmi, ko-ko jèrè
[03:08.88]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings