Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Alpha & Omega (feat. Bhadboi OML)

👤 Zlatan 🎼 Symbol of Hope ⏱️ 3:04
🎵 2245 characters
⏱️ 3:04 duration
🆔 ID: 25400260

📜 Lyrics

(Chelo, Chelo)
Ibilẹ
(Yeah-yeah, yeah)
(Oh-ah, yeah-yeah, yeah)

Hustle every day and night (swa)
Pray make dem no stain my white
Even when I go all the way (still many people go backbite)
The future bright
Every likkle thing will be alright
You can never know who is who (pray make Oluwa dey my side)

Mo pe Alpha ati Omega
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko ma lọ bee
Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ

Iya ati Baba Lọla lo bi mi, ṣugbọn mo tunra mi bi
Ẹlẹdaa mi fẹ sun, mo dabara bo, ko ji
Darukọ iṣẹ jama-jama, nnkan ti mi o ṣe ri
Mo gbe pọnnpọ pa sẹ, diẹ lo ku sẹ ki igun mi pa l'ori
Baba Pastor o tete mọ pe Zanku n fo window lọ si show, dogboru pẹlu Kito
Fẹmi Brookey lo kọkọ mu mi lọ si studio
Orin wèrè mo kọ, awọn temi l'odun bi Kopiko
Mi o le gbagbe awọn nigga mi, awọn l'ọn ginger mi

Ti n ba wa owo studio ti, wọn a t'owo b'apo knicker mi
Ten toes on my grind, nisin, mo d'ọmọ to sabi
Up Agbede ni Ikorodu, awọn temi l'Onigari
That time!
Oh my Lordy, wọn ni, "Ko le lọ far"
Wọn ni, "Bawo lẹni ti o niṣẹ ṣe ma san tithes?" (Awọn bastard)
Orukọ ọmọ mi, Toluwalaṣẹ
Unstoppable, bo wun wọn k'ọn gb'ajẹ

Mo pe Alpha ati Omega
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko ma lọ bee
Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ

Mo pada d'ọmọ t'ọn fi n yangan, ọmọ t'ọn fin tọrọ
Irọ o da, ma m'ẹnu le, ọmọ j'ọmọ lọ
Pain in the ass ti o common fun awọn doubting Thomas
Eewo ti mu wọn l'ẹnu, aje, wọn le s'ọrọ mọ
I go dey always remember

When I wan cook, but gas no dey cylinder
I was born to do wonders
But ogun idile no wan gimme chance
Never you say never, my life story na big ginger
"Symbol of Hope," e dey play, e dey show
Steady motivation f'awọn temi ninu hood

Mo pe Alpha ati Omega (ah-ah)
Afi ko dide ja
Afi ko ṣaanu mi
Afi ko ja fun mi
Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
Ko yẹ ko ma lọ bee
Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ

Ko yẹ ko ma lọ bee
Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ-ẹ

⏱️ Synced Lyrics

[00:06.96] (Chelo, Chelo)
[00:08.90] Ibilẹ
[00:12.20] (Yeah-yeah, yeah)
[00:14.07] (Oh-ah, yeah-yeah, yeah)
[00:18.28] Hustle every day and night (swa)
[00:20.58] Pray make dem no stain my white
[00:22.92] Even when I go all the way (still many people go backbite)
[00:28.13] The future bright
[00:29.77] Every likkle thing will be alright
[00:32.16] You can never know who is who (pray make Oluwa dey my side)
[00:37.15] Mo pe Alpha ati Omega
[00:39.56] Afi ko dide ja
[00:41.92] Afi ko ṣaanu mi
[00:44.16] Afi ko ja fun mi
[00:46.59] Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
[00:48.87] Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
[00:51.16] Ko yẹ ko ma lọ bee
[00:53.33] Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ
[00:56.04] Iya ati Baba Lọla lo bi mi, ṣugbọn mo tunra mi bi
[00:59.11] Ẹlẹdaa mi fẹ sun, mo dabara bo, ko ji
[01:01.49] Darukọ iṣẹ jama-jama, nnkan ti mi o ṣe ri
[01:03.45] Mo gbe pọnnpọ pa sẹ, diẹ lo ku sẹ ki igun mi pa l'ori
[01:06.09] Baba Pastor o tete mọ pe Zanku n fo window lọ si show, dogboru pẹlu Kito
[01:10.83] Fẹmi Brookey lo kọkọ mu mi lọ si studio
[01:12.98] Orin wèrè mo kọ, awọn temi l'odun bi Kopiko
[01:15.02] Mi o le gbagbe awọn nigga mi, awọn l'ọn ginger mi
[01:17.56] Ti n ba wa owo studio ti, wọn a t'owo b'apo knicker mi
[01:20.06] Ten toes on my grind, nisin, mo d'ọmọ to sabi
[01:22.26] Up Agbede ni Ikorodu, awọn temi l'Onigari
[01:24.72] That time!
[01:25.35] Oh my Lordy, wọn ni, "Ko le lọ far"
[01:27.23] Wọn ni, "Bawo lẹni ti o niṣẹ ṣe ma san tithes?" (Awọn bastard)
[01:30.02] Orukọ ọmọ mi, Toluwalaṣẹ
[01:32.24] Unstoppable, bo wun wọn k'ọn gb'ajẹ
[01:33.51] Mo pe Alpha ati Omega
[01:36.01] Afi ko dide ja
[01:38.31] Afi ko ṣaanu mi
[01:40.72] Afi ko ja fun mi
[01:43.04] Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
[01:45.49] Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
[01:47.78] Ko yẹ ko ma lọ bee
[01:49.97] Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ
[01:52.25] Mo pada d'ọmọ t'ọn fi n yangan, ọmọ t'ọn fin tọrọ
[01:54.91] Irọ o da, ma m'ẹnu le, ọmọ j'ọmọ lọ
[01:57.23] Pain in the ass ti o common fun awọn doubting Thomas
[01:59.65] Eewo ti mu wọn l'ẹnu, aje, wọn le s'ọrọ mọ
[02:01.96] I go dey always remember
[02:04.10] When I wan cook, but gas no dey cylinder
[02:06.78] I was born to do wonders
[02:08.70] But ogun idile no wan gimme chance
[02:11.99] Never you say never, my life story na big ginger
[02:15.97] "Symbol of Hope," e dey play, e dey show
[02:18.24] Steady motivation f'awọn temi ninu hood
[02:20.69] Mo pe Alpha ati Omega (ah-ah)
[02:23.09] Afi ko dide ja
[02:25.44] Afi ko ṣaanu mi
[02:27.70] Afi ko ja fun mi
[02:30.26] Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi
[02:32.59] Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni
[02:34.87] Ko yẹ ko ma lọ bee
[02:36.99] Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ
[02:42.04] Ko yẹ ko ma lọ bee
[02:46.00] Ko dẹ yẹ ko ma lọ bẹẹ-ẹ
[02:49.92]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings