Kape Laye
🎵 685 characters
⏱️ 4:51 duration
🆔 ID: 28256103
📜 Lyrics
Kaape laye
Ka lo Ile aye titi
Ko ni Kaye gbo ooooooo
Aye lole lo niyan keee gbo
Igba ta gbe laye
Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
Keledua je kaa le pitan rere
Omi aye to ru siwa seyin o
Awon kan gbaye
Won pitan iṣẹ titi
Wọn pitan ìṣòro kolopin rárá
Ọrọ wọn o Papa jasayo o'mase
O'jojo aye ni won fojú sògbérè ẹkun
Titi ikú fi p'awọn won o lenu dupẹ
Omi aye to ru siwa seyin ooo
Awọn kan gb'ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t'oda ayé
Ọrọ' ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni
wọn l'ayé wọn f'ogo rẹ fún satani nii
Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o'mase o'mase
Òun gbogbo toni kaluku ní wọn fi fesu

⏱️ Synced Lyrics
[00:34.44] Kaape laye
[00:37.90] Ka lo Ile aye titi
[00:41.30] Ko ni Kaye gbo ooooooo
[00:47.71] Aye lole lo niyan keee gbo
[00:53.92] Igba ta gbe laye
[00:56.94] Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
[01:03.29] Keledua je kaa le pitan rere
[01:10.79] Omi aye to ru siwa seyin o
[01:43.88] Awon kan gbaye
[01:46.25] Won pitan iṣẹ titi
[01:49.50] Wọn pitan ìṣòro kolopin rárá
[01:55.73] Ọrọ wọn o Papa jasayo o'mase
[02:02.05] O'jojo aye ni won fojú sògbérè ẹkun
[02:11.96] Titi ikú fi p'awọn won o lenu dupẹ
[03:15.80] Omi aye to ru siwa seyin ooo
[03:16.48] Awọn kan gb'ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t'oda ayé
[03:27.51] Ọrọ' ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni
[03:36.19] Wọn l'ayé wọn f'ogo rẹ fún satani nii
[03:44.36] Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o'mase o'mase
[03:50.94] Òun gbogbo toni kaluku ní wọn fi fesu
[04:46.49]