Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Àkọ́kọ́

👤 Brymo 🎼 9: Èsan ⏱️ 2:44
🎵 1386 characters
⏱️ 2:44 duration
🆔 ID: 5687019

📜 Lyrics

Èmi ni, èmi lẹni náà
Ọkùnrin mẹ'ta àtààbọ' tán forin kọ
Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
Ọkùnrin mẹ'rin àtààbọ', wọn ń tẹnu mọ
Mo lanu, mo sọ'rọ'
Mo yọ àáké, mo fọ' ọ'rọ'
Ọmọ ọlọọfọọrọ
Mo j'àkàrà ọfọọrọ

Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn màmá gan ń sòró ní pópó

Wọn lémi l'àkọkọ
Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh
Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh
Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh

Èmi ni ọkùnrin náà
Táwọn màjèsín ń sọ pé m'orin gan
Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
Gbogbo ará àdúgbò ló ń tẹnu mọ
Èmi bàbá olówó
Mo ṣòwò, mo jèrè
Ìwà àti ọpọlọ ló ń lò
Àwọn ọ'tá ti ru póò

Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn ọmọge ń rèdí ní pópó

Wọ'n lémi l'àkọ'kọ'
(Ìwọ l'àkọ'kọ')
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Iwo l'àkókó oh-oh)
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ'
(Ìwọ l'àkọ'kọ')
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
(Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)

⏱️ Synced Lyrics

[00:11.29] Èmi ni, èmi lẹni náà
[00:14.65] Ọkùnrin mẹ'ta àtààbọ' tán forin kọ
[00:17.39] Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
[00:20.03] Ọkùnrin mẹ'rin àtààbọ', wọn ń tẹnu mọ
[00:23.06] Mo lanu, mo sọ'rọ'
[00:25.77] Mo yọ àáké, mo fọ' ọ'rọ'
[00:29.21] Ọmọ ọlọọfọọrọ
[00:31.35] Mo j'àkàrà ọfọọrọ
[00:34.25] Èmi ni áà, emi ni óò
[00:37.03] Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro
[00:39.79] Èmi ni yáà, èmi ni yóò
[00:42.75] Àwọn màmá gan ń sòró ní pópó
[00:45.40] Wọn lémi l'àkọkọ
[00:48.72] Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh
[00:56.74] Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh
[01:02.79] Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh
[01:07.76] Èmi ni ọkùnrin náà
[01:12.03] Táwọn màjèsín ń sọ pé m'orin gan
[01:14.94] Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
[01:17.09] Gbogbo ará àdúgbò ló ń tẹnu mọ
[01:20.15] Èmi bàbá olówó
[01:22.85] Mo ṣòwò, mo jèrè
[01:26.08] Ìwà àti ọpọlọ ló ń lò
[01:28.43] Àwọn ọ'tá ti ru póò
[01:30.82] Èmi ni áà, emi ni óò
[01:34.42] Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro
[01:37.14] Èmi ni yáà, èmi ni yóò
[01:39.86] Àwọn ọmọge ń rèdí ní pópó
[01:42.73] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ'
[01:46.12] (Ìwọ l'àkọ'kọ')
[01:48.74] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[01:51.72] (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
[01:54.17] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[01:57.12] (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
[01:59.74] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[02:02.44] (Iwo l'àkókó oh-oh)
[02:05.18] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ'
[02:08.16] (Ìwọ l'àkọ'kọ')
[02:10.50] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[02:13.54] (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
[02:15.90] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[02:18.88] (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
[02:21.58] Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh
[02:24.18] (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
[02:27.40]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings