Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́

👤 Brymo 🎼 9: Èsan ⏱️ 2:51
🎵 606 characters
⏱️ 2:51 duration
🆔 ID: 5687022

📜 Lyrics

Ìyàwó kàn mí npa mi lo, gere

Wọn l'olufoya ni mí oh oh
Ọkùnrin tó lè fẹ mẹta, merin ah ah
Pe mo sà, mo sà, ẹrú dé mí mọlẹ

Ọkàn mi ti fọ' wẹwẹ
Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'lẹ'

Nígbà míràn n'ifẹ fẹ ma wù
Láti ibì ẹwà kóró ẹ'mi mi
Kò tún ní wú

Mo mọ bò ṣe burúkú

O fi lè lẹ tìpẹ'tipẹ'

Má yọ apá mí fún ọ
Òun ló n'ba ẹ' nnú jẹ
Tí 'nu mi ndún
Kò dára

Ọkàn mi ti fò wẹwẹ

Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'

Nígbà míràn, n'ifẹ fẹ má wù
Láti ibì ẹwà kọ'rọ' èmi mi
Kò tún ní wú

⏱️ Synced Lyrics

[00:15.25] Ìyàwó kàn mí npa mi lo, gere
[00:20.21]
[00:22.78] Wọn l'olufoya ni mí oh oh
[00:30.53] Ọkùnrin tó lè fẹ mẹta, merin ah ah
[00:38.29] Pe mo sà, mo sà, ẹrú dé mí mọlẹ
[00:45.25] Ọkàn mi ti fọ' wẹwẹ
[00:51.07]
[00:53.56] Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'lẹ'
[01:00.71] Nígbà míràn n'ifẹ fẹ ma wù
[01:07.48] Láti ibì ẹwà kóró ẹ'mi mi
[01:11.67] Kò tún ní wú
[01:14.46]
[01:17.90] Mo mọ bò ṣe burúkú
[01:23.11] O fi lè lẹ tìpẹ'tipẹ'
[01:27.91]
[01:31.40] Má yọ apá mí fún ọ
[01:38.42] Òun ló n'ba ẹ' nnú jẹ
[01:40.29] Tí 'nu mi ndún
[01:43.26] Kò dára
[01:48.02] Ọkàn mi ti fò wẹwẹ
[01:53.04]
[01:55.33] Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'
[02:00.09]
[02:03.65] Nígbà míràn, n'ifẹ fẹ má wù
[02:09.50] Láti ibì ẹwà kọ'rọ' èmi mi
[02:14.51] Kò tún ní wú
[02:16.27]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings