Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Ààrẹ

👤 Brymo 🎼 9: Èsan ⏱️ 1:59
🎵 1273 characters
⏱️ 1:59 duration
🆔 ID: 5687027

📜 Lyrics

Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá

Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá

Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o

Ẹku owurọ o
Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí

Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí, àwọn ọmọ éèès!
Wọ'n ti jà wọ"gboro
Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé
Wọ'n ti ń dáná sun oko
Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ'
Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun

Ẹ gbélé yín o
Ẹ ṣọ'ra yín o
Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ'
Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó
Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o
Láyọ' o, ẹ ṣé

Ààrẹ ń bọ' l'ájò
Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore

Ààrẹ ń bọ' l'ájò
Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore

⏱️ Synced Lyrics

[00:11.26] Eré òkúta àti gíláàsì
[00:15.25] Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
[00:18.05] Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá
[00:21.00] Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
[00:24.06] Eré òkúta àti gíláàsì
[00:27.00] Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
[00:29.79] Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá
[00:32.76] Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
[00:35.78] Eré òkúta àti gíláàsì
[00:38.87] Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
[00:41.82] Ọlọ'ọ'pá wá o
[00:42.72] Ẹku owurọ o
[00:43.37] Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí
[00:46.96] Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí, àwọn ọmọ éèès!
[00:49.94] Wọ'n ti jà wọ"gboro
[00:52.76] Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé
[00:54.41] Wọ'n ti ń dáná sun oko
[00:55.96] Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ'
[00:58.58] Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun
[01:00.46] Ẹ gbélé yín o
[01:01.95] Ẹ ṣọ'ra yín o
[01:03.43] Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ'
[01:05.14] Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó
[01:08.10] Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o
[01:10.68] Láyọ' o, ẹ ṣé
[01:14.11]
[01:17.04] Ààrẹ ń bọ' l'ájò
[01:20.99] Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
[01:25.33] Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
[01:29.68] Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
[01:32.01] Orí mi ló gbé mi k'ore
[01:34.56] Ààrẹ ń bọ' l'ájò
[01:38.65] Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
[01:43.16] Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
[01:47.52] Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
[01:50.15] Orí mi ló gbé mi k'ore
[01:52.23]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings