Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Sabi

👤 MohBad 🎼 Blessed ⏱️ 2:19
🎵 1947 characters
⏱️ 2:19 duration
🆔 ID: 5752675

📜 Lyrics

(No one is sleeker)

Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi
K'owá w'orí mi, k'òtò saasi
Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o (ehn-ehn, ehn)
K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán, ò b'omi sí garri
Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?
Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o
Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o
Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko'rè oko dé'lé o
Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o
Mo fíìmù wọn fọn fèrè o
Nínú àyé, mí o kéré o
T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o

Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o
K'owá w'orí mi, k'òtò saasi
Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)
K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
Huh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?
Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o
Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o
Tińbá ṣíṣẹ́, kiń má ko'rè oko dé'lé o
Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o
Mo fíìmù wọn fọn fèrè o
Nínú àyé, mí o kéré
T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o

I will exalt You, Lord
For You have lifted me up
Has not let my foes to rejoice over me
(Timi Jay on the track)

⏱️ Synced Lyrics

[00:06.96] (No one is sleeker)
[00:09.82] Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi
[00:12.45] K'owá w'orí mi, k'òtò saasi
[00:14.73] Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
[00:17.02] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
[00:19.35] Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o (ehn-ehn, ehn)
[00:21.60] K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
[00:24.10] Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
[00:26.01] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
[00:28.92] Uh, ọmọ ológo tó sabi
[00:30.83] Ọmọ gbéra tán, ò b'omi sí garri
[00:33.69] Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
[00:35.69] Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
[00:38.47] Uh, ọmọ ológo tó sabi
[00:40.65] Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
[00:43.00] Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
[00:45.53] Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
[00:47.34] Huh, kí lódé o jere o?
[00:50.16] Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o
[00:52.39] Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o
[00:54.88] Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko'rè oko dé'lé o
[00:56.70] Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o
[00:59.99] Mo fíìmù wọn fọn fèrè o
[01:02.76] Nínú àyé, mí o kéré o
[01:04.74] T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o
[01:06.99] Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o
[01:09.40] K'owá w'orí mi, k'òtò saasi
[01:11.63] Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
[01:14.00] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
[01:16.26] Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)
[01:18.69] K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
[01:21.07] Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati
[01:23.19] Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o
[01:26.04] Uh, ọmọ ológo tó sabi
[01:28.20] Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
[01:30.71] Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
[01:33.09] Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
[01:35.11] Huh, ọmọ ológo tó sabi
[01:37.92] Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri
[01:40.10] Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof
[01:42.63] Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
[01:44.55] Huh, kí lódé o jere o?
[01:47.20] Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o
[01:49.32] Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o
[01:52.12] Tińbá ṣíṣẹ́, kiń má ko'rè oko dé'lé o
[01:53.95] Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o
[01:57.22] Mo fíìmù wọn fọn fèrè o
[01:59.66] Nínú àyé, mí o kéré
[02:01.70] T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o
[02:03.29] I will exalt You, Lord
[02:05.55] For You have lifted me up
[02:08.18] Has not let my foes to rejoice over me
[02:13.39] (Timi Jay on the track)
[02:16.67]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings