Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Evergreen Yoruba Songs of Praise 2

๐Ÿ‘ค EmmaOMG โ€ข ๐ŸŽผ OhEmGee Praise Sessions, Vol. 1 โ€ข โฑ๏ธ 9:27
๐ŸŽต 1723 characters
โฑ๏ธ 9:27 duration
๐Ÿ†” ID: 6800864

๐Ÿ“œ Lyrics

Ope ye o o Baba
Ope ye o o Omo
Ope ye o o Baba
Ope ye o o Omo
Eledumare a s'ore kari aye
O s'ore f'Oba o tun se t'ijoye l'oto
Ko ma gbagbe emi omo re rara
Ope ye o o Baba
(REPEAT)

Opelope re (2ce)
Aye i ba yeye mi
Opelope re... hallelujah
(REPEAT)

Titi laelae iwo l'Oba
Titi ayeraye iwo l'Oba o
Niwon igba ti aye yoo ma wa
Jesu Kristi iwo l'Oba o
(REPEAT)

Emi yoo ma yin o
Emi yoo ma gbe o ga
Iwo sha ma s'atileyin mi
Emi o ma gbe o ga
(REPEAT 2ce)

Mo ki o wipe o se
Olorun eleda mi o
Mo ki o wipe o se o
Olorun gbogbo aye... emi ki o(REPEAT)
Iwa laye mi loni
E e maa i se mi mo o se mi
A mo tori mo r'anu gba lowo Baba o
Mo wa f'emi imoore han
Mo ki o wipe o se
Olorun eleda mi o
Mo ki o wipe o se o
Olorun gbogbo aye

Oloore mi o se o
Olurapada o seun
Eniyan i ba maa yin Jesu
Fun'se rere at'iyanu re
(REPEAT)

Oluwa, Oluwa wa (2ce)
Oruko re ti niyin to
(REPEAT)

Okan ni emi ati Baba mi jasi (2ce)
Jesu n be pelu mi
O duro ti mi gboin-gboin
Ajinde ati iye
Baba n be pelu mi
Okan ni emi ati Baba mi jasi (2ce)
Jesu n be pelu mi
O duro ti mi gboin-gboin
Ajinde ati iye
O duro ti mi o

Alagbara l'Olorun mi
Alagbara ni Jesu mi o
To ba ti soro bee naa lo n ri
Alagbara l'Olorun mi
(REPEAT)

Call: So f'oro re jafara.Resp: Ko f'oro mi jafara (4ce)
Call: Oloore ni Baba o.Resp: Oloore ni Baba to dami (4ce)

Call: Jesu olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye
Call: Olorun Babalola olomi iye re
O.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye
Call: Jesu Kristi olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye
Call: Oba awon oba olomi iye re o.
Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye
Call: Jesu olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye

Call: Hallelujah, hallelujah (2ce).hallelujah
Resp: Hallelujah...(24ce)

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings