Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

B'o Se Nd'agba

👤 Beautiful Nubia and The Roots Renaissance Band 🎼 Táabákú ⏱️ 4:20
🎵 1282 characters
⏱️ 4:20 duration
🆔 ID: 9152945

📜 Lyrics

Bí'nú rẹ bá dùn k'o rọra ṣe
L'ọ'jọ' ìkorò má fa'jú ro
Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o
Bo r'ẹ'ni nyọ' k'o bá wọn ṣe, ẹni ń sunkún ò, fà wọn mọ'ra
Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn

M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe
Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ'
M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe

B'o l'ọ'rọ' púpọ' má fi ṣ'akọ, bí ò sí o, má ṣè'lara
Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o

Àríyọ' mi ò, ọmọ rere, ìtùnú òbí rẹ' l'ọ'jọ' ogbó

Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ Akin, má ro'jú, má ṣ'ọ'le
M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
Mo ní b'ẹ ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe kún wọn ní'gbìmọ' ọ'tẹ'
M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
Moní b'o ṣe ń làkàkà, ọmọ, má ro'jú, má ṣ'ọ'le
M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe

Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o
Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn
M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ'
M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe

⏱️ Synced Lyrics

[01:02.72] Bí'nú rẹ bá dùn k'o rọra ṣe
[01:07.16] L'ọ'jọ' ìkorò má fa'jú ro
[01:11.32] Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o
[01:20.37] Bo r'ẹ'ni nyọ' k'o bá wọn ṣe, ẹni ń sunkún ò, fà wọn mọ'ra
[01:29.40] Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn
[01:34.39] M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe
[01:38.45] Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ'
[01:43.58] M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
[01:46.30]
[02:46.99] B'o l'ọ'rọ' púpọ' má fi ṣ'akọ, bí ò sí o, má ṣè'lara
[02:55.75] Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o
[03:04.44] Àríyọ' mi ò, ọmọ rere, ìtùnú òbí rẹ' l'ọ'jọ' ogbó
[03:12.94] Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ Akin, má ro'jú, má ṣ'ọ'le
[03:17.84] M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
[03:21.94] Mo ní b'ẹ ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe kún wọn ní'gbìmọ' ọ'tẹ'
[03:26.58] M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
[03:30.54] Moní b'o ṣe ń làkàkà, ọmọ, má ro'jú, má ṣ'ọ'le
[03:35.31] M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe
[03:39.47] Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o
[03:48.12] Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn
[03:52.72] M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
[03:56.84] Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ'
[04:01.76] M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
[04:04.17]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings