Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Imole II

๐Ÿ‘ค Sola Allyson โ€ข ๐ŸŽผ Isodotun โ€ข โฑ๏ธ 7:03
๐ŸŽต 1700 characters
โฑ๏ธ 7:03 duration
๐Ÿ†” ID: 9174130

๐Ÿ“œ Lyrics

Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S'ibi Imole
Jesu! Eni t'O wa
Ife Baba
S'eni to fe d'omo

Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S'ibi Imole
Jesu! Eni t'O wa
Ife Baba
S'eni to fe d'omo

Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S'ibi Imole
Jesu! Eni t'O wa
Ife Baba
S'eni to fe d'omo

Imole, lati 'nu Imole
O wa lati da wa pada
S'ona Imole
Ookun to gb' aye
Ko je k' 'on mo Imole
Won dite mo O, Ife Baba
Olorun ninu eniyan
Eniyan ninu Olorun
Ilekun awon aguntan
S'inu ile aanu
Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s'odo Baba
B' aye ti n fi fun ni ko
Imole s'ookun aye mi
Olu se 'wosan emi mi

Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S'ibi Imole
Jesu! Eni t'O wa
Ife Baba
S'eni to fe d'omo

(Emi mi ke rara, mo pe Jesuuu!)
Jesu! Imole!
Ategun ati afara
S'ibi Imole
Jesu! Eni t'O wa
Ife Baba
S'eni to fe d'omo

Eni wa Imole
Won n ri Imole
Won o mo Imole
Won n dite Imole
Irora yen po gan
Eje at' omi san gan
Sibe O s' agbawi fun wa
Pe Baba dariji won
Won o mo n t' 'on se
S' a ti mo 'n a n se
Baba, dariji wa o, nitori Imole
Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole ***
O ni "Iya wo omo re, Omo wo iya Re"
O kigbe lohun rara:
"Olorun mi, eese t' O ko mi i le..."
"Eese to ju mi le, eese t' O yin mi nu?"
Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un
Awon to wa Imole o, won fi 'ya je Imole
O ba pari, O pari!
Imole f' emi E s'owo Baba
O pari!

Nitori Imole
Aso ikele ya o
Nitori Imole
A le pe Baba ni Baba
Nitori Imole
Isa oku d'ofo
Eni ba fe le wa d'omo

Jesu! Oga Ogo!
Olori Ogun Orun!
Omo Alade Alaafia!
Alase Orun!
Aye Baba!
Baba laaye o!
Baba laye!
Aye mi, Tire ni
Tan Imole nipase mi
Ogo mi k'o f'ogo fun O
Ola mi k'o bu ola fun O!

Jesu! Iwo ni 'Mole!
Iwo ni Afara!
S'ibi ategun Imole
Jesu! Iwo ni Eni naa t'O wa
Mo juba Re, Eni to so mi d'omo

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:14.40] Jesu! Imole!
[00:20.78] Ategun ati Afara
[00:24.06] S'ibi Imole
[00:27.88] Jesu! Eni t'O wa
[00:34.18] Ife Baba
[00:36.83] S'eni to fe d'omo
[00:41.10] Jesu! Imole!
[00:47.43] Ategun ati Afara
[00:50.41] S'ibi Imole
[00:53.53] Jesu! Eni t'O wa
[01:00.84] Ife Baba
[01:03.05] S'eni to fe d'omo
[01:06.84] Jesu! Imole!
[01:13.42] Ategun ati Afara
[01:17.57] S'ibi Imole
[01:21.29] Jesu! Eni t'O wa
[01:27.67] Ife Baba
[01:30.40] S'eni to fe d'omo
[01:35.38] Imole, lati 'nu Imole
[01:40.96] O wa lati da wa pada
[01:43.98] S'ona Imole
[01:48.04] Ookun to gb' aye
[01:51.03] Ko je k' 'on mo Imole
[01:55.02] Won dite mo O, Ife Baba
[02:01.49] Olorun ninu eniyan
[02:04.68] Eniyan ninu Olorun
[02:09.95] Ilekun awon aguntan
[02:11.07] S'inu ile aanu
[02:13.76] Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s'odo Baba
[02:18.35] B' aye ti n fi fun ni ko
[02:20.60] Imole s'ookun aye mi
[02:23.67] Olu se 'wosan emi mi
[02:27.71] Jesu! Imole!
[02:34.77] Ategun ati Afara
[02:37.64] S'ibi Imole
[02:40.79] Jesu! Eni t'O wa
[02:48.52] Ife Baba
[02:50.45] S'eni to fe d'omo
[02:53.72] (Emi mi ke rara, mo pe Jesuuu!)
[02:55.71] Jesu! Imole!
[03:00.76] Ategun ati afara
[03:04.86] S'ibi Imole
[03:08.76] Jesu! Eni t'O wa
[03:13.11] Ife Baba
[03:17.07] S'eni to fe d'omo
[03:22.13] Eni wa Imole
[03:25.09] Won n ri Imole
[03:28.43] Won o mo Imole
[03:31.43] Won n dite Imole
[03:34.88] Irora yen po gan
[03:38.20] Eje at' omi san gan
[03:42.11] Sibe O s' agbawi fun wa
[03:45.72] Pe Baba dariji won
[03:48.82] Won o mo n t' 'on se
[03:51.53] S' a ti mo 'n a n se
[03:54.71] Baba, dariji wa o, nitori Imole
[04:02.30] Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole ***
[04:08.16] O ni "Iya wo omo re, Omo wo iya Re"
[04:14.97] O kigbe lohun rara:
[04:18.14] "Olorun mi, eese t' O ko mi i le..."
[04:20.51] "Eese to ju mi le, eese t' O yin mi nu?"
[04:29.27] Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un
[04:36.81] Awon to wa Imole o, won fi 'ya je Imole
[04:42.53] O ba pari, O pari!
[04:52.54] Imole f' emi E s'owo Baba
[04:53.55] O pari!
[04:55.61] Nitori Imole
[05:02.55] Aso ikele ya o
[05:05.29] Nitori Imole
[05:08.93] A le pe Baba ni Baba
[05:11.66] Nitori Imole
[05:15.66] Isa oku d'ofo
[05:18.60] Eni ba fe le wa d'omo
[05:22.93] Jesu! Oga Ogo!
[05:28.66] Olori Ogun Orun!
[05:31.68] Omo Alade Alaafia!
[05:35.95] Alase Orun!
[05:39.27] Aye Baba!
[05:41.91] Baba laaye o!
[05:45.28] Baba laye!
[05:48.64] Aye mi, Tire ni
[05:51.91] Tan Imole nipase mi
[05:54.98] Ogo mi k'o f'ogo fun O
[05:58.36] Ola mi k'o bu ola fun O!
[06:02.62] Jesu! Iwo ni 'Mole!
[06:09.61] Iwo ni Afara!
[06:11.95] S'ibi ategun Imole
[06:16.31] Jesu! Iwo ni Eni naa t'O wa
[06:23.37] Mo juba Re, Eni to so mi d'omo
[06:43.32]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings