Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Iye

๐Ÿ‘ค Sola Allyson โ€ข ๐ŸŽผ Isodotun โ€ข โฑ๏ธ 4:11
๐ŸŽต 628 characters
โฑ๏ธ 4:11 duration
๐Ÿ†” ID: 9174174

๐Ÿ“œ Lyrics

Iye a wa
Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o
Iye a wa

Iye a wa
Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o
Iye a wa

Iye de
Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o
Iye de

Iye de
Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o
Iye de

O wa ooo, O wa
O de ooo, O de
O wa ooo, O wa
O de ooo, O de

Aanu de
Alaanu f'aanu s'aanu, O mu temi ko mi
Aanu de

Aanu de
Alaanu f'aanu s'aanu, O mu temi ko mi
Aanu de

O de ooo, O de

Isegun wa
Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o
Isegun wa

Isegun de
Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o
Isegun de

O wa ooo; O wa, O de ooo; O de

Iye a wa
Iye de
Eni to ni iye lodo, O pin temi ko mi o
Iye de

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings