Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Mimo L'oluwa (Medley)

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Angeli Mi โ€ข โฑ๏ธ 11:02
๐ŸŽต 1703 characters
โฑ๏ธ 11:02 duration
๐Ÿ†” ID: 9241656

๐Ÿ“œ Lyrics

Mimo l'Oluwa o (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)
Mimo l'Oluwa (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)
Agbagba merinlelogun (mimo)
N'origun merin aye o (mimo)
Ati oke, ati ile (mimo)
Seri nwo ke o (mimo)
Tani yo gori oke Oluwa (mimo)
Tabi tani yo duro ni'be o (mimo)
Eni ti o ni owo mimo (mimo)
Ati aya funfun (mimo)
Mimo l'Oluwa (mimo)
Mimo o mimo (mimo)
Mimo o mimo o mimo (mimo)
Mimo o funfun nene ni (mimo)
Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo)
Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun
Oba ti oni emi inu eniyan pata
Oni kokoro aye l' lowo
Adagodo emi gbogbo eniyan
Olu kogan orun ajosi edumare
Ibinigbi awuwo bi atele
Opa tiri kole o ko orun
Minimi ojo ti jeki ara odehin
Orun wawa ti o pada bo si po
Olorun ti o 'so osupa di ale ti oun t' oru
Oba ti ose ohun gbogbo ni asiko ni asiko
Oba ti ole fi eni 'yi ti, ti a ole fi eyi re ti laila
Are la Oba ti eni kan obi, ti obi omo kari gbogbo aye koropodo
Olowo ori gbogbo aye pata pata ni
Oniwa funfun Oba dake se un ti enikan ole se un si
Inu ogo gangan ni oti fo owu
Ol' ogo ti oju ogo lo ni
Ki abi o ko si
Emi o je fi o sere
Afi eni ti o ba fe gba query l'odore
Mi oje fi oju di o
Oba ti ose wo lo ju wo
Oti e leti
Aledibaje ni o
Baba la kun Baba mi
Ole gbi yeke
Gbogbo eni ti oba mo riri Oluwa
Ete riba ewa riri fun Oba nki shi
Ibere ati opin Olorun ajanakun ti mi igbo kiji kiji kiji
Ti abubu ti a le buto to posi ni gbogbo ojo
Eje ka sapa fun Oba rere ti aba mo riri
Emi inu awon woli mimo
A tobi tan alainiye ko koja kika
Terere ko ja riri to
Gigun l' alopi
Ailetunwo, adawunro, adawunso, adawunse
Olulu awon orun, oke la ari owu masiti

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:36.44] Mimo l'Oluwa o (mimo)
[00:41.04] Angeli nwo mike o (mimo)
[00:44.25] Awon orun nwo mike (mimo)
[00:47.57] Egbagbeje irawo o (mimo)
[00:50.46] Mimo l'Oluwa (mimo)
[00:54.10] Angeli nwo mike o (mimo)
[00:57.09] Awon orun nwo mike (mimo)
[01:00.53] Egbagbeje irawo o (mimo)
[01:03.77] Agbagba merinlelogun (mimo)
[01:06.90] N'origun merin aye o (mimo)
[01:10.47] Ati oke, ati ile (mimo)
[01:13.18] Seri nwo ke o (mimo)
[01:16.52] Tani yo gori oke Oluwa (mimo)
[01:19.88] Tabi tani yo duro ni'be o (mimo)
[01:22.81] Eni ti o ni owo mimo (mimo)
[01:26.35] Ati aya funfun (mimo)
[01:29.65] Mimo l'Oluwa (mimo)
[01:32.66] Mimo o mimo (mimo)
[01:36.08] Mimo o mimo o mimo (mimo)
[01:39.07] Mimo o funfun nene ni (mimo)
[01:42.75] Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo)
[01:46.47] Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun
[01:50.18] Oba ti oni emi inu eniyan pata
[01:52.49] Oni kokoro aye l' lowo
[01:54.14] Adagodo emi gbogbo eniyan
[01:55.53] Olu kogan orun ajosi edumare
[01:59.58] Ibinigbi awuwo bi atele
[02:01.57] Opa tiri kole o ko orun
[02:03.52] Minimi ojo ti jeki ara odehin
[02:05.58] Orun wawa ti o pada bo si po
[02:10.33] Olorun ti o 'so osupa di ale ti oun t' oru
[02:12.37] Oba ti ose ohun gbogbo ni asiko ni asiko
[02:14.30] Oba ti ole fi eni 'yi ti, ti a ole fi eyi re ti laila
[02:19.07] Are la Oba ti eni kan obi, ti obi omo kari gbogbo aye koropodo
[02:23.44] Olowo ori gbogbo aye pata pata ni
[02:25.77] Oniwa funfun Oba dake se un ti enikan ole se un si
[02:34.96] Inu ogo gangan ni oti fo owu
[02:37.81] Ol' ogo ti oju ogo lo ni
[02:39.59] Ki abi o ko si
[02:40.94] Emi o je fi o sere
[02:42.03] Afi eni ti o ba fe gba query l'odore
[02:43.98] Mi oje fi oju di o
[02:45.62] Oba ti ose wo lo ju wo
[02:46.63] Oti e leti
[02:49.75] Aledibaje ni o
[02:51.34] Baba la kun Baba mi
[02:52.69] Ole gbi yeke
[02:54.39] Gbogbo eni ti oba mo riri Oluwa
[02:57.69] Ete riba ewa riri fun Oba nki shi
[03:00.27] Ibere ati opin Olorun ajanakun ti mi igbo kiji kiji kiji
[03:05.96] Ti abubu ti a le buto to posi ni gbogbo ojo
[03:11.73] Eje ka sapa fun Oba rere ti aba mo riri
[03:14.44] Emi inu awon woli mimo
[03:16.75] A tobi tan alainiye ko koja kika
[03:20.22] Terere ko ja riri to
[03:22.47] Gigun l' alopi
[03:23.49] Ailetunwo, adawunro, adawunso, adawunse
[03:27.10] Olulu awon orun, oke la ari owu masiti
[03:54.34]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings