Nigbati Mo Ro O
๐ต 2809 characters
โฑ๏ธ 6:27 duration
๐ ID: 9243579
๐ Lyrics
Lati inu oyun
Titi di omo owo o
Igba mo wa lomo owo
Awon ota gba wipe iku o pa mi
mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakawe
Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba o
Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
Mo wa ri pe o oga o pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ogun ti eniyan ja n'agba, o poju Ogun ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo ooo
Oju ogun laye je feni to waye o wa se rere
Mo wa ronu jinle
Aanu re lori aye mi
Emi ri pe o ga o, pupo
Igba ti mi ro anu re lo ri mi
mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro anu re lo ri mi

Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
Iya to je mi, o je ko je mi gbe o, baba o seun.
A pe omo lowo eyin
oluso agun fun mi
Olorun iwo ni
Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo
O gbe mi so ke gogoro, Osuba re o baba
eyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbe
Igba ti mi ro ife nla re Lori mi
mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ife nla re lori mi
mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Olorun to ga owa loke
Olorun to be ninu aye
Okere titi, ogba mimo eniyan
Owa lotun wa, owa lo si wa
Ayika wa gbogbo, owa ni be
Ohun ni olorun, afeti lu Kara
Larin alawo dudu o n sise e lo
Eyin re eniyan, mo rin ise re
Alawo funfun won teriba fun
Alayi mo n kon, won beere wipe
Tani olorun, ta lolorun
Ayanfe ema da won lo wun pe
Ibi gbogbo lo wa eh
Olorun agbaye
Ibi gbogbo lo wa eh
Ani ko si ibiti oju olorun ko to
Ibi gbogbo lo wa
Olorun nla apejuba, arayerorun
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lolorun gbe
Ibi gbogbo lo wa
O nbe laye, emi awon woli to to
Ibi gbogbo lo wa
Oro gbe inu omo eniyan fo mu
Ibi gbogbo lo wa
Oti saju aye de, omo inu aye ati eyin aye
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa olodumare
Ibi gbogbo lo wa
O nbe larin awon angeli mimo
Ibi gbogbo lo wa
Ko si ibiti e pe olorun si ti o wa oh
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa baba oh
Ibi gbogbo lo wa
Olorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa baba
Ibi gbogbo lo wa
O nbe lokan re ti o ba gba laye
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo, ibi gbogbo lo wa

โฑ๏ธ Synced Lyrics
[00:22.81] Lati inu oyun
[00:24.37] Titi di omo owo o
[00:27.40] Igba mo wa lomo owo
[00:29.05] Awon ota gba wipe iku o pa mi
[00:32.14] Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
[00:37.05] Baba o sho mi, ore re yi o lakawe
[00:41.97] Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
[00:47.07] Titi mo fi wa di agbalagba o
[00:52.14] Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
[00:56.87] Mo wa ri pe o oga o pupo
[01:02.07] Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
[01:06.39] Mori pe oga, mo ri pe o ga
[01:08.83] Mo ri pe o ga Baba.
[01:12.03] Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
[01:16.38] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[01:22.26] Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
[01:26.42] Mori pe oga, more ri pe o ga
[01:29.87] Mo ri pe o ga Baba.
[01:32.72] Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
[01:37.26] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[01:42.80] Ogun ti eniyan ja n'agba, o poju Ogun ewe lo
[01:47.77] Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
[01:52.83] Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo ooo
[01:57.76] Oju ogun laye je feni to waye o wa se rere
[02:02.36] Mo wa ronu jinle
[02:04.51] Aanu re lori aye mi
[02:07.79] Emi ri pe o ga o, pupo
[02:12.73] Igba ti mi ro anu re lo ri mi
[02:17.12] Mori pe oga, mo ri pe o ga
[02:19.67] Mo ri pe o ga Baba.
[02:23.02] Igba ti mo ro anu re lo ri mi
[02:27.13] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[02:32.95] Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
[02:37.23] Mori pe oga, mo ri pe o ga
[02:39.69] Mo ri pe o ga Baba.
[02:42.99] Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
[02:46.39] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[02:52.38]
[03:11.86] Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
[03:16.86] Iya to je mi, o je ko je mi gbe o, baba o seun.
[03:21.93] A pe omo lowo eyin
[03:23.44] Oluso agun fun mi
[03:24.74] Olorun iwo ni
[03:27.02] Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo
[03:31.87] O gbe mi so ke gogoro, Osuba re o baba
[03:37.58] Eyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbe
[03:42.60] Igba ti mi ro ife nla re Lori mi
[03:46.74] Mori pe oga, more ri pe o ga
[03:49.60] Mo ri pe o ga Baba.
[03:53.07] Igba ti mo ro ife nla re lori mi
[03:57.36] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[04:03.67] Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
[04:07.57] Mori pe oga, more ri pe o ga Baba.
[04:13.03] Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
[04:17.30] Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
[04:22.55]
[04:41.23] Olorun to ga owa loke
[04:43.60] Olorun to be ninu aye
[04:45.82] Okere titi, ogba mimo eniyan
[04:48.23] Owa lotun wa, owa lo si wa
[04:51.04] Ayika wa gbogbo, owa ni be
[04:53.04] Ohun ni olorun, afeti lu Kara
[04:55.31] Larin alawo dudu o n sise e lo
[04:57.86] Eyin re eniyan, mo rin ise re
[05:00.38] Alawo funfun won teriba fun
[05:02.87] Alayi mo n kon, won beere wipe
[05:05.49] Tani olorun, ta lolorun
[05:07.47] Ayanfe ema da won lo wun pe
[05:10.56] Ibi gbogbo lo wa eh
[05:15.48] Olorun agbaye
[05:16.74] Ibi gbogbo lo wa eh
[05:20.22] Ani ko si ibiti oju olorun ko to
[05:22.92] Ibi gbogbo lo wa
[05:24.58] Olorun nla apejuba, arayerorun
[05:27.77] Ibi gbogbo lo wa
[05:29.64] Ibi gbogbo lolorun gbe
[05:32.66] Ibi gbogbo lo wa
[05:34.25] O nbe laye, emi awon woli to to
[05:37.54] Ibi gbogbo lo wa
[05:39.50] Oro gbe inu omo eniyan fo mu
[05:42.76] Ibi gbogbo lo wa
[05:43.91] Oti saju aye de, omo inu aye ati eyin aye
[05:47.27] Ibi gbogbo lo wa
[05:48.63] Ibi gbogbo lo wa olodumare
[05:51.78] Ibi gbogbo lo wa
[05:53.01] O nbe larin awon angeli mimo
[05:56.24] Ibi gbogbo lo wa
[05:57.52] Ko si ibiti e pe olorun si ti o wa oh
[06:01.01] Ibi gbogbo lo wa
[06:02.56] Ibi gbogbo lo wa baba oh
[06:05.96] Ibi gbogbo lo wa
[06:07.45] Olorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa baba
[06:10.51] Ibi gbogbo lo wa
[06:12.17] O nbe lokan re ti o ba gba laye
[06:15.82] Ibi gbogbo lo wa
[06:16.99] Ibi gbogbo, ibi gbogbo lo wa
[06:20.03] Ibi gbogbo lo wa
[06:20.45]