Nitori Awa
🎵 562 characters
⏱️ 3:09 duration
🆔 ID: 9249127
📜 Lyrics
Wan lọ gb'ẹbọ ni oríta mẹta
Nitori awa
Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ
Nitori awa
Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ
Nitori awa
Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ
Nitori awa
Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
Nitori awa
T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
Nitori awa
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
Ẹ ma wulẹ sáré ka
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
Ẹ ma wulẹ sáré ka
Nitori awa
Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ
Nitori awa
Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ
Nitori awa
Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ
Nitori awa
Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
Nitori awa
T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
Nitori awa
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
Ẹ ma wulẹ sáré ka
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
Ẹ ma wulẹ sáré ka
⏱️ Synced Lyrics
[00:01.03] Wan lọ gb'ẹbọ ni oríta mẹta
[00:02.43] Nitori awa
[00:17.14] Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ
[00:18.88] Nitori awa
[00:38.96] Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ
[00:41.80] Nitori awa
[00:56.14] Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ
[00:58.50] Nitori awa
[01:10.57] Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
[01:12.89] Nitori awa
[01:25.68] T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
[01:27.51] Nitori awa
[01:33.23] Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
[01:36.57] Kuru kẹrẹ
[01:37.86] Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
[01:41.36] Ogun o ran wa o
[01:43.62] Ẹ ma wulẹ sáré ka
[02:27.65] Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
[02:29.82] Kuru kẹrẹ
[02:31.18] Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
[02:34.52] Ogun o ran wa o
[02:36.76] Ẹ ma wulẹ sáré ka
[02:41.58]
[00:02.43] Nitori awa
[00:17.14] Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ
[00:18.88] Nitori awa
[00:38.96] Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ
[00:41.80] Nitori awa
[00:56.14] Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ
[00:58.50] Nitori awa
[01:10.57] Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
[01:12.89] Nitori awa
[01:25.68] T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
[01:27.51] Nitori awa
[01:33.23] Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
[01:36.57] Kuru kẹrẹ
[01:37.86] Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
[01:41.36] Ogun o ran wa o
[01:43.62] Ẹ ma wulẹ sáré ka
[02:27.65] Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
[02:29.82] Kuru kẹrẹ
[02:31.18] Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
[02:34.52] Ogun o ran wa o
[02:36.76] Ẹ ma wulẹ sáré ka
[02:41.58]