Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Oluwa Lo Yan Mi

๐Ÿ‘ค King Sunny Ade โ€ข ๐ŸŽผ Classics, Vol. 1: Let Them Say & Edide โ€ข โฑ๏ธ 2:35
๐ŸŽต 818 characters
โฑ๏ธ 2:35 duration
๐Ÿ†” ID: 9249473

๐Ÿ“œ Lyrics

Gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo

Oluwa lo pe mi lo yan mi wa se, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo

Kita kita ko ran, giri giri ko ran o
Kita kita o ran o, giri giri ko ran o
Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye
Ori mi maa je n si won w'aye l'aye lasan lasan
Eda mi ma je n se akobata fun egbe mi
Tori kita kita o ran o, giri giri ko ran o
Kita kita o ran la, giri giri o ran o
Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye

Emi ti gbo ohun Oluwa ti o wipe
Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
Aye le ma sata
Aba, Let them say

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:15.09] Gbogbo awon ayanfe e lo se logo
[00:18.43] Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
[00:26.70]
[00:54.81] Oluwa lo pe mi lo yan mi wa se, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
[01:02.42] Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
[01:16.73] Kita kita ko ran, giri giri ko ran o
[01:26.19] Kita kita o ran o, giri giri ko ran o
[01:32.98] Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
[01:36.65] Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye
[01:42.09] Ori mi maa je n si won w'aye l'aye lasan lasan
[01:47.73] Eda mi ma je n se akobata fun egbe mi
[01:52.47] Tori kita kita o ran o, giri giri ko ran o
[02:02.27] Kita kita o ran la, giri giri o ran o
[02:07.66] Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
[02:11.33] Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye
[02:17.15] Emi ti gbo ohun Oluwa ti o wipe
[02:19.15] Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
[02:26.71] Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
[02:33.96] Aye le ma sata
[02:35.38] Aba, Let them say
[02:35.38]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings