Ebenezeri (feat. EMMAOMG)
🎵 2433 characters
⏱️ 4:54 duration
🆔 ID: 9267409
📜 Lyrics
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de
Ka'ma jo o, kayo, ka fogo folu
Ninu irinkerido mi laye, eh
Íwọ lo ba mi sé
Alubarika lo wa mi ri
Emi kọ, isẹ ọlọrun ni
Ewu gbógbó ti mo la kọja
Ki ma yí se agbara mi
Atinuda ti mo di, lo njẹ ki dupe ore
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (nibi ti ẹ ran wa lọwọ de)
Ka'ma jo o, k'ayọ, ka fogo folu (Ebenezeri)
Ebenezeri wa re oo
Ema ma se ẹse
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye (oluwa lo ni iranlọwọ)
Ogo t'aye rí ti wọn polongo
Irẹ lo ba wa se
Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kọ (oh my God)
Ẹse ibi t'ẹti bẹrẹ
Ẹse ibi t'ẹba de
Adupẹ Oluwa
Ibi t'ẹmu wa lọ
Tori, ibasepe oluwa koti wa niti wa ooo
Nibo la ba jasi
Amo ni sẹ yin, adupẹ at'ọpẹ da
Tori wipe, awọn kan gbẹkẹlé kẹkẹ
Awọn kan gbẹkẹlé ẹṣin
Awa ta gbekele ooo
Ibi tomu wa de, ibi ogo ni
Lase wi pe
Orin halleluya
Orin hosana ooo
Orin Ebenezer
Hosana lo gbẹ'nu wa kan (ẹkorin ebenezeri o)
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (ibi tẹ ran wa lọwọ de)
Ka'ma jo o k'ayọ ka fogo folu (ẹsẹ ibi te ti beere)
Ebenezeri wa re oo (ibi ti ẹ ba wa de)
Ema ma se ẹse
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni ìmọ ati oye (Oluwa lo ni iranlọwọ)
Ogo ti aye rí ti wọn polongo
Irẹ lo ba wa ṣe
Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kan
Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (ka'dupẹ)
Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (oh-oh-oh)
Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ
Oh-oh-oh-oh, Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa
Tori pe
Àgbọn igbẹ ibunkun aidiyẹle
To fi fun wa ah ah ah
La ṣe ndupe (ẹ ho iho ayọ si oluwa)
Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh)
Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (ọkan mi yin oluwa logo)
Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ (mo mu ore wa sọdọ rẹ, mo panu pọ, adupẹ)
Oh-oh-oh-oh, a Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (tori abu bu tan ore rẹ)
Aidiyẹle
To fi fun wa ah ah ah
La ṣe ndupe
Moni, agbón igbẹ ibunkun aidiyẹle
To fi fun wa ah ah ah
La ṣe ndupe
Gbogbo aye mi sọrọ ogo rẹ
Tori abukun tan ore
To se fun mi, oh oh ah eh
La se ndupé
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka'ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re oo
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
Ogo t'aye ri ti wọn polongo

⏱️ Synced Lyrics
[00:00.14] Ebenezeri wa re oo
[00:02.88] Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de
[00:06.05] Ka'ma jo o, kayo, ka fogo folu
[00:24.59] Ninu irinkerido mi laye, eh
[00:28.32] Íwọ lo ba mi sé
[00:30.38] Alubarika lo wa mi ri
[00:33.33] Emi kọ, isẹ ọlọrun ni
[00:36.48] Ewu gbógbó ti mo la kọja
[00:39.55] Ki ma yí se agbara mi
[00:42.13] Atinuda ti mo di, lo njẹ ki dupe ore
[00:45.97] Ebenezeri wa re oo
[00:48.47] Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (nibi ti ẹ ran wa lọwọ de)
[00:52.25] Ka'ma jo o, k'ayọ, ka fogo folu (Ebenezeri)
[00:57.16] Ebenezeri wa re oo
[01:00.06] Ema ma se ẹse
[01:02.65] Kima nse nipa agbara
[01:05.96] Oluwa loni imo ati oye (oluwa lo ni iranlọwọ)
[01:08.82] Ogo t'aye rí ti wọn polongo
[01:11.80] Irẹ lo ba wa se
[01:14.04] Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kọ (oh my God)
[01:20.15] Ẹse ibi t'ẹti bẹrẹ
[01:23.34] Ẹse ibi t'ẹba de
[01:25.88] Adupẹ Oluwa
[01:28.83] Ibi t'ẹmu wa lọ
[01:32.12] Tori, ibasepe oluwa koti wa niti wa ooo
[01:37.04] Nibo la ba jasi
[01:39.20] Amo ni sẹ yin, adupẹ at'ọpẹ da
[01:42.08] Tori wipe, awọn kan gbẹkẹlé kẹkẹ
[01:46.27] Awọn kan gbẹkẹlé ẹṣin
[01:48.52] Awa ta gbekele ooo
[01:50.43] Ibi tomu wa de, ibi ogo ni
[01:53.62] Lase wi pe
[01:55.01] Orin halleluya
[01:57.39] Orin hosana ooo
[01:59.91] Orin Ebenezer
[02:02.13] Hosana lo gbẹ'nu wa kan (ẹkorin ebenezeri o)
[02:05.97] Ebenezeri wa re oo
[02:08.75] Nibi ti ẹ ran wa lọwọ de (ibi tẹ ran wa lọwọ de)
[02:11.02] Ka'ma jo o k'ayọ ka fogo folu (ẹsẹ ibi te ti beere)
[02:16.92] Ebenezeri wa re oo (ibi ti ẹ ba wa de)
[02:20.08] Ema ma se ẹse
[02:22.80] Kima nse nipa agbara
[02:25.10] Oluwa loni ìmọ ati oye (Oluwa lo ni iranlọwọ)
[02:27.83] Ogo ti aye rí ti wọn polongo
[02:31.76] Irẹ lo ba wa ṣe
[02:34.17] Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kan
[02:39.20] Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (ka'dupẹ)
[02:45.12] Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (oh-oh-oh)
[02:51.48] Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ
[02:56.59] Oh-oh-oh-oh, Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa
[03:01.66] Tori pe
[03:02.83] Àgbọn igbẹ ibunkun aidiyẹle
[03:06.03] To fi fun wa ah ah ah
[03:11.34] La ṣe ndupe (ẹ ho iho ayọ si oluwa)
[03:15.17] Oh-oh-oh-oh, ka panu pọ ka'dupẹ (oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh)
[03:20.26] Oh-oh-oh-oh, ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (ọkan mi yin oluwa logo)
[03:26.50] Oh oh oh oh, a pànu po ka'dupẹ (mo mu ore wa sọdọ rẹ, mo panu pọ, adupẹ)
[03:32.99] Oh-oh-oh-oh, a Ka kọrin ayo ka mọ pẹ wa (tori abu bu tan ore rẹ)
[03:38.93] Aidiyẹle
[03:40.46] To fi fun wa ah ah ah
[03:45.10] La ṣe ndupe
[03:48.17] Moni, agbón igbẹ ibunkun aidiyẹle
[03:52.28] To fi fun wa ah ah ah
[03:57.01] La ṣe ndupe
[03:58.57] Gbogbo aye mi sọrọ ogo rẹ
[04:01.10] Tori abukun tan ore
[04:03.45] To se fun mi, oh oh ah eh
[04:08.44] La se ndupé
[04:11.45] Ebenezeri wa re oo
[04:14.67] Nibi ti e ran wa lowo de
[04:17.07] Ka'ma jo o kayo ka fogo folu
[04:22.74] Ebenezeri wa re oo
[04:25.98] Ema ma se ese
[04:28.07] Kima nse nipa agbara
[04:31.38] Oluwa loni imo ati oye
[04:33.93] Ogo t'aye ri ti wọn polongo
[04:37.33] Irẹ lo ba wa ṣe
[04:39.89] Orin halleluya, hossana lo gbẹ'nu wa kan
[04:44.57]