Mo Se Ba
๐ต 2229 characters
โฑ๏ธ 5:28 duration
๐ ID: 9268481
๐ Lyrics
Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo
Emi juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo
Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo
Eniyan meji nbi omo kan soso
Okan soso na a ma la won l'ogun gidi
Obi le bimo meji k'enu won ma ka won rara
Iwo mighty olorun ti ipa re ka gbogbo aye
(Iwo lo tobe)
Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo
Won f'eniyan je Baale t'enu re o ka baa
Oba n je lori ilu ti ilu o de tori e toro
Ginigini ti wu a re wo ti ko r'oju ara re
Aye o'niyan orun n wa riri ni oruko re
Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo
Iwo l'olorun
Iwo l'oluwa
Iwo l'olorun to pe ohun gbogbo wa
Oro to lase lori ohun gbogbo to da o pata
Eni ti o le mu ko si ninu ise owo re
O lagbara lori eda patapata

Mo se ba oluda nibo lo o le yi aye si
Talo to o
Talo ju o
To ba pase f'ojo ko yi pada
Kabiesi tani o bi oo
Olorun eran ara
Agbara re lo s'edidi ohun gbogbo
Iwo to s'oku di iye
Eleri idi
Sababi orun to gbe aye duro wawa
Olodumare
Oye k'eda gbogbo beru re
Olorun ogo
Oye k'eda gbogbo beru re
Iwo to ni eemi ati emi inu
Ipinlese aye orun wa ni kawo re
Baba oo
Oye k'eda gbogbo beru re
Olodumare
Oye k'eda ma wa riri fun
Alagbara giga
Oye k'eda ma wa riri fun
Iwo to le pa to le ji
Ototan
Sikun aye sikun orun
Ta lo le gba lowo re
Aaah
Oye k'eda ma wa riri fun
Olodumare
Oye k'eda gbogbo beru re
Awimayewun alagbara ju lo
Oye k'eda gbogbo beru re
Iwo to ni eemi ati emi inu
Ipinlese aye orun wa ni kawo re
Alagbara oo
Oye k'eda gbogbo beru re
Olodumare
Oye k'eda ma wa riri fun
Onise iyanu
Oye k'eda ma wa riri fun
Iwo to le pa to le ji
Ototan
Sikun ogbon sikun apadi
Nbe lowo re
Baba ooo
Oye k'eda ma wa riri fun
Iba re o Olodumare
Ogo ma ni fun oo

โฑ๏ธ Synced Lyrics
[00:18.28] Mo se ba f'olorun agbaye
[00:22.41] Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo
[00:26.85] Emi juba f'olorun to da orun at'aye papo
[00:31.08] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[00:35.34] Mo se ba f'olorun agbaye
[00:39.90] Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
[00:44.06] Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
[00:48.56] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[00:56.82] Eniyan meji nbi omo kan soso
[01:01.38] Okan soso na a ma la won l'ogun gidi
[01:05.97] Obi le bimo meji k'enu won ma ka won rara
[01:10.19] Iwo mighty olorun ti ipa re ka gbogbo aye
[01:14.41] (Iwo lo tobe)
[01:14.90] Mo se ba f'olorun agbaye
[01:18.82] Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
[01:23.70] Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
[01:27.77] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[01:34.73] Won f'eniyan je Baale t'enu re o ka baa
[01:38.74] Oba n je lori ilu ti ilu o de tori e toro
[01:42.75] Ginigini ti wu a re wo ti ko r'oju ara re
[01:47.00] Aye o'niyan orun n wa riri ni oruko re
[01:51.52] Mo se ba f'olorun agbaye
[01:55.85] Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
[02:00.51] Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
[02:05.04] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[02:26.43] Iwo l'olorun
[02:28.47] Iwo l'oluwa
[02:30.31] Iwo l'olorun to pe ohun gbogbo wa
[02:34.64] Oro to lase lori ohun gbogbo to da o pata
[02:39.12] Eni ti o le mu ko si ninu ise owo re
[02:43.44] O lagbara lori eda patapata
[02:48.52] Mo se ba f'olorun agbaye
[02:52.25] Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
[02:57.09] Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
[03:01.60] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[03:05.88] Mo se ba f'olorun agbaye
[03:09.99] Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo
[03:14.46] Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
[03:19.14] To lagbara lo'ori eda gbogbo
[03:22.89] Mo se ba oluda nibo lo o le yi aye si
[03:27.44] Talo to o
[03:29.91] Talo ju o
[03:31.99] To ba pase f'ojo ko yi pada
[03:34.25] Kabiesi tani o bi oo
[03:35.93] Olorun eran ara
[03:38.22] Agbara re lo s'edidi ohun gbogbo
[03:42.44] Iwo to s'oku di iye
[03:45.58] Eleri idi
[03:47.24] Sababi orun to gbe aye duro wawa
[03:51.78] Olodumare
[03:53.44] Oye k'eda gbogbo beru re
[03:56.54] Olorun ogo
[03:58.20] Oye k'eda gbogbo beru re
[04:01.60] Iwo to ni eemi ati emi inu
[04:05.45] Ipinlese aye orun wa ni kawo re
[04:09.45] Baba oo
[04:11.11] Oye k'eda gbogbo beru re
[04:14.24] Olodumare
[04:15.67] Oye k'eda ma wa riri fun
[04:18.45] Alagbara giga
[04:20.26] Oye k'eda ma wa riri fun
[04:22.81] Iwo to le pa to le ji
[04:26.06] Ototan
[04:27.30] Sikun aye sikun orun
[04:29.89] Ta lo le gba lowo re
[04:31.57] Aaah
[04:32.98] Oye k'eda ma wa riri fun
[04:35.87] Olodumare
[04:37.13] Oye k'eda gbogbo beru re
[04:40.23] Awimayewun alagbara ju lo
[04:41.97] Oye k'eda gbogbo beru re
[04:44.17] Iwo to ni eemi ati emi inu
[04:48.94] Ipinlese aye orun wa ni kawo re
[04:53.27] Alagbara oo
[04:54.42] Oye k'eda gbogbo beru re
[04:57.56] Olodumare
[04:58.69] Oye k'eda ma wa riri fun
[05:01.96] Onise iyanu
[05:03.06] Oye k'eda ma wa riri fun
[05:06.13] Iwo to le pa to le ji
[05:09.54] Ototan
[05:10.60] Sikun ogbon sikun apadi
[05:13.18] Nbe lowo re
[05:14.84] Baba ooo
[05:16.40] Oye k'eda ma wa riri fun
[05:20.24] Iba re o Olodumare
[05:22.58] Ogo ma ni fun oo
[05:25.31]