Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Guoguo

👤 Beautiful Nubia 🎼 Lord of Letters ⏱️ 5:07
🎵 1815 characters
⏱️ 5:07 duration
🆔 ID: 9268679

📜 Lyrics

Bí 'gbà bà mí dùn
Òun gbogbo a dá bí ere
Gbogbo àyé a má yìn o
Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o
Bí 'gbà bà yi pere
Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ
Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah
Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o

Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)

K'alẹ, kò lé dùn
Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ
Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ
Kà má fí t'ẹní p'ọlá o
Kò s'òun ta o rí-rí
A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú
A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ
Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun)

Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)

Ilé wúrà ń d áhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)

Ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)

Woah-oh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)

Ilé wúrà
Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn
(Mo rí o ná) mo rí o ná
Ilé wúrà
Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn

⏱️ Synced Lyrics

[00:40.72] Bí 'gbà bà mí dùn
[00:45.53] Òun gbogbo a dá bí ere
[00:50.64] Gbogbo àyé a má yìn o
[00:55.34] Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o
[01:00.11] Bí 'gbà bà yi pere
[01:05.16] Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ
[01:09.78] Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah
[01:14.46] Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o
[01:20.40] Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[01:25.57] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[01:29.85] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[01:33.98] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[01:38.00]
[01:58.34] K'alẹ, kò lé dùn
[02:03.22] Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ
[02:08.02] Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ
[02:12.98] Kà má fí t'ẹní p'ọlá o
[02:17.27] Kò s'òun ta o rí-rí
[02:21.74] A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú
[02:26.06] A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ
[02:31.75] Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun)
[02:36.95] Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[02:42.00] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[02:46.26] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[02:50.31] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[02:54.34]
[03:34.47] Ilé wúrà ń d áhòrò (ilé wúrà)
[03:39.43] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[03:43.38] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[03:47.41] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[03:53.14] Ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
[03:57.72] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[04:02.11] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[04:06.16] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[04:11.16] Woah-oh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
[04:16.45] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[04:20.61] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[04:24.67] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[04:32.82] Ilé wúrà
[04:37.39] Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn
[04:44.04] (Mo rí o ná) mo rí o ná
[04:51.33] Ilé wúrà
[04:56.07] Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn
[05:00.90]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings