Guoguo
🎵 2044 characters
⏱️ 5:25 duration
🆔 ID: 9268680
📜 Lyrics
Bí 'gbà bà mí dùn
Òun gbogbo a dá bí ere
Gbogbo àyé a má yìn o
Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o
Bí 'gbà bà yi pere
Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ
Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah
Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o
Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
K'alẹ, kò lé dùn
Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ
Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ
Kà má fí t'ẹní p'ọlá o
Kò s'òun ta o rí-rí
A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú
A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ
Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun)

Ilé wúràa má d áhòrò (ilé wúrà)

Ṣé bí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)

Ohh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)

Ohh, ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)

Ilé wúrà
Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn
Mo rí o ná
Ilé wúrà
Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn

⏱️ Synced Lyrics
[00:48.79] Bí 'gbà bà mí dùn
[00:53.34] Òun gbogbo a dá bí ere
[00:57.93] Gbogbo àyé a má yìn o
[01:02.67] Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o
[01:07.43] Bí 'gbà bà yi pere
[01:12.03] Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ
[01:16.25] Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah
[01:20.73] Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o
[01:26.49] Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[01:31.40] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[01:35.60] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[01:39.56] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[01:44.45]
[02:02.87] K'alẹ, kò lé dùn
[02:07.53] Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ
[02:12.15] Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ
[02:16.74] Kà má fí t'ẹní p'ọlá o
[02:21.33] Kò s'òun ta o rí-rí
[02:25.77] A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú
[02:30.19] A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ
[02:35.31] Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun)
[02:40.54] Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[02:45.40] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[02:49.58] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[02:53.57] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[02:59.28] Ilé wúràa má d áhòrò (ilé wúrà)
[03:03.77] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[03:07.83] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[03:11.91] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[03:16.25]
[03:53.33] Ṣé bí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[03:58.40] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[04:02.52] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[04:06.63] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[04:10.74] Ohh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
[04:16.35] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[04:20.51] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[04:24.36] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[04:29.29] Ohh, ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
[04:34.47] Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
[04:38.59] Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
[04:42.38] Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná)
[04:46.17]
[04:50.06] Ilé wúrà
[04:54.58] Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn
[04:58.36]
[05:02.95] Mo rí o ná
[05:07.53] Ilé wúrà
[05:11.92] Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn
[05:15.56]
[05:20.49] Mo rí o ná
[05:22.08]