Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Adura Mi

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Igbowo Eda โ€ข โฑ๏ธ 6:39
๐ŸŽต 1954 characters
โฑ๏ธ 6:39 duration
๐Ÿ†” ID: 9313166

๐Ÿ“œ Lyrics

Eyi nikan
L'adura mi
Si Olu Aseda mi

Eyi nikan
L'adura mi
Mo ti mo ona iye yi na

Mi o ni ye'se
Mi o ni pada
Emi o ni si lo
Kododo aye ma fe mo oju mi
Ju ibi t'ayo mi wa lo

Amin
Amin
Amin
O amin oo

Eyi nikan le mi nbere
Nigba ti mo n mi
Ko na t'oluwa mu mi rin yi o
K'emi ma se amoju sonu
Kin le d'ebute ogo ayanmo
K'ogo baba ko tan de opin
Imole ko tan de opin aye
Fun oruko re nikan

(O amin o)
O amin
O amin
O amin
O amin o

Eyi l'ohun temi n bere
Anu ati abo re
Owo re at'otito re
Ko tan mi l'aye d'ogbo
Ani ko se Asa at'Apata
Ko ma yo wo ni pe ja mi
Eni sare ibi le mi
Ko f'ori ara re gbe
Gbe'be mi s'ase
O amin o

(Amin o)
O amin
O amin
O amin
O amin o
(Amin)

Eyi l'ohun temi n bere
Awon omo to fun mi
Ki won sin o
Iwo nikan
Ki won ko se rere laye
K'alaafia ati ife re
Ma joba ni ile wa
Opopona majemu ayeraye
Ni ka wa o fo titi
Alaafia ogbo tutu
Ni ipin tawa lodo aseda

(Beeni ko ri oo)
O amin
O amin
O amin
O amin o

Eyi nikan l'adura mi
Owo oluwa ko kun mi pupo
Ki ina mi jo fun isoji si
Labe asiapada bo re
Ka sa ko pada l'ohun kan
K'ero ijoba re ko po si
To ba si de oko iyawo
Awa yo ba o joba
Adura mi ni
Ko se oo

(O se O se)
O amin
O amin
O amin
O amin o

Adura mi ma ti gba
Baba mi a gbo
Ohun ti emi bere
Baba ti se oo
Ogede ki n gb'odo ko ya gan (beeni)
Baba mi a gbo
Elegbede f'owo lu'gi o dun jaye oo
Baba ti se oo

Omo o le bere akara ka fun lo kuta oo
Baba mi a gbo
Igbagbo ninu Jesu kin doju tini
Baba ti se o
Ohun gangan ti mo n bere
Baba mi a gbo
Ati iran de ran mi Olorun la o ma sin titi
Baba ti se o

Ke mi o mo fo ojo aye mi si Oluwa
Baba mi a gbo
Oore ofe ati iferan Olugbala mi si
Baba ti se o
Kin ma joko l'ese re nigba gbogbo ko eko oo
Baba mi a gbo
K'emi se yi di ojo ogbo tutu ni mo bere oo
Baba ti se o

Iran peregun won ki rin wowo kin ku dale (beeni)
Baba mi a gbo
Ka le wa san mi ju owuro lo Olu nla mo be o
Baba ti se o

(eeeh amin oo)
O amin
O amin
O amin
O amin o

Ase
Amin
Ase o
Ema s'amin ase

Amin
Amin
Ase

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:24.59] Eyi nikan
[00:25.78] L'adura mi
[00:27.43] Si Olu Aseda mi
[00:30.07] Eyi nikan
[00:31.70] L'adura mi
[00:33.58] Mo ti mo ona iye yi na
[00:36.38] Mi o ni ye'se
[00:37.71] Mi o ni pada
[00:39.27] Emi o ni si lo
[00:42.40] Kododo aye ma fe mo oju mi
[00:45.85] Ju ibi t'ayo mi wa lo
[00:49.65] Amin
[00:52.76] Amin
[00:55.38] Amin
[00:58.08] O amin oo
[01:13.15] Eyi nikan le mi nbere
[01:15.48] Nigba ti mo n mi
[01:18.08] Ko na t'oluwa mu mi rin yi o
[01:21.28] K'emi ma se amoju sonu
[01:23.93] Kin le d'ebute ogo ayanmo
[01:27.14] K'ogo baba ko tan de opin
[01:29.78] Imole ko tan de opin aye
[01:33.27] Fun oruko re nikan
[01:36.63] (O amin o)
[01:37.48] O amin
[01:39.53] O amin
[01:42.16] O amin
[01:45.50] O amin o
[01:57.78] Eyi l'ohun temi n bere
[02:00.33] Anu ati abo re
[02:03.56] Owo re at'otito re
[02:06.36] Ko tan mi l'aye d'ogbo
[02:09.22] Ani ko se Asa at'Apata
[02:12.10] Ko ma yo wo ni pe ja mi
[02:15.23] Eni sare ibi le mi
[02:18.32] Ko f'ori ara re gbe
[02:20.97] Gbe'be mi s'ase
[02:25.02] O amin o
[02:26.93] (Amin o)
[02:28.34] O amin
[02:30.64] O amin
[02:34.19] O amin
[02:36.80] O amin o
[02:39.19] (Amin)
[03:06.37] Eyi l'ohun temi n bere
[03:09.26] Awon omo to fun mi
[03:12.04] Ki won sin o
[03:13.84] Iwo nikan
[03:15.35] Ki won ko se rere laye
[03:18.13] K'alaafia ati ife re
[03:21.28] Ma joba ni ile wa
[03:23.98] Opopona majemu ayeraye
[03:27.20] Ni ka wa o fo titi
[03:30.15] Alaafia ogbo tutu
[03:32.81] Ni ipin tawa lodo aseda
[03:36.28] (Beeni ko ri oo)
[03:37.37] O amin
[03:39.67] O amin
[03:42.47] O amin
[03:44.74] O amin o
[03:48.70] Eyi nikan l'adura mi
[03:51.53] Owo oluwa ko kun mi pupo
[03:54.71] Ki ina mi jo fun isoji si
[03:57.23] Labe asiapada bo re
[04:00.14] Ka sa ko pada l'ohun kan
[04:03.44] K'ero ijoba re ko po si
[04:06.24] To ba si de oko iyawo
[04:09.41] Awa yo ba o joba
[04:12.56] Adura mi ni
[04:15.49] Ko se oo
[04:18.26] (O se O se)
[04:19.39] O amin
[04:22.08] O amin
[04:24.85] O amin
[04:27.88] O amin o
[04:30.55] Adura mi ma ti gba
[04:33.42] Baba mi a gbo
[04:36.62] Ohun ti emi bere
[04:39.79] Baba ti se oo
[04:42.68] Ogede ki n gb'odo ko ya gan (beeni)
[04:46.44] Baba mi a gbo
[04:48.56] Elegbede f'owo lu'gi o dun jaye oo
[04:52.45] Baba ti se oo
[04:54.24] Omo o le bere akara ka fun lo kuta oo
[04:58.00] Baba mi a gbo
[05:00.66] Igbagbo ninu Jesu kin doju tini
[05:04.01] Baba ti se o
[05:06.48] Ohun gangan ti mo n bere
[05:10.44] Baba mi a gbo
[05:12.49] Ati iran de ran mi Olorun la o ma sin titi
[05:16.22] Baba ti se o
[05:17.94] Ke mi o mo fo ojo aye mi si Oluwa
[05:21.73] Baba mi a gbo
[05:24.22] Oore ofe ati iferan Olugbala mi si
[05:28.26] Baba ti se o
[05:30.17] Kin ma joko l'ese re nigba gbogbo ko eko oo
[05:33.96] Baba mi a gbo
[05:36.11] K'emi se yi di ojo ogbo tutu ni mo bere oo
[05:40.07] Baba ti se o
[05:42.13] Iran peregun won ki rin wowo kin ku dale (beeni)
[05:46.79] Baba mi a gbo
[05:48.44] Ka le wa san mi ju owuro lo Olu nla mo be o
[05:52.13] Baba ti se o
[05:53.88] (eeeh amin oo)
[05:55.39] O amin
[05:57.51] O amin
[05:59.81] O amin
[06:03.82] O amin o
[06:08.83] Ase
[06:11.40] Amin
[06:14.69] Ase o
[06:17.56] Ema s'amin ase
[06:23.66] Amin
[06:26.25] Amin
[06:29.12] Ase
[06:30.98]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings