Moriamo
🎵 2606 characters
⏱️ 3:33 duration
🆔 ID: 9417917
📜 Lyrics
Ọmọ Adefi
Ọmọ Adefa lókè Iresi
(Moriamo Alege) (Moriamo)
Ìyá bàbá mí, sún re
Ní ilé àyé, 1980 something
(The Beat Handle)
Damilare, èmi l'àkọ́bí bàa mi, kí Qudus tó dì Qdot
Ìyá àti bàbá mí tí Jáà ó tí pẹ
Kín tó wa'yé lótí ní wọn le fẹ'ra wọn
Okun ẹbí t'oba Jáà, welder kàn ó lé jo (Alagbe)
K'Ọlọrun f'ọrun kẹ Moriamo, ìyá bàbá mí
Moriamo, ọmọ Alege
Ìyá má ń gb'ọmọ gẹ-gẹ ní
Màmá ó gbé mí sílẹ̀ k'èyàn kan-kan tọju mí
Moriamo, ọrun re
Mí ó gbàgbé okò Alado o, l'ọnà Erugbabu
Okò obi yí grandma tí fọ lójú kàn
Bóyà ń torí obi tó mà tá ní muri kàn
Ìyá yí tún padà s'oko, ada, t'ohun t'ọkọ ní
Orí mí à wú to bà pé mí lọkọ' mí
Ọjọ rí jẹ, pẹlú ọjọ rírí mú
Màmá ma ń r'oka pẹlú ẹfọ Bọkọlu
Omi odò là má ń mú (omi odò là má ń mú)
Labúlé Ado, labúlé Ado oh (labúlé Ado)
(Abúlé Ado) abúlé wá ó jìnà si Shagamu
À ńpadà s'oko ní motor jamu (ó má ṣée)
Màmá bà ń pariwo, "Damilare, ọmọlọmọ ní, ẹ bà ń gbé"
Ó mà ṣeé, ó mà ṣee (ó mà ṣeé)
Ọjọ yẹn ní mo mọ pé ìyá yí kọ lo bí mí
Moriamo Alege (Moriamo)
Moriamo Alege (Moria oh)
Moriamo Alege, ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ
Moriamo Alege (Moriamo)
Moriamo Alege (Moria oh)
Moriamo Alege
Ìyá bàbá mí, ọrun rè rẹ (Moriamo)
Ọrun re rẹ (Moria oh)
Hmm, ọjọ re bí ana nígbà t'ikú wọlé dé
Ìyá yí tí r'ikú lóṣe ní ń b'ode lọ
K'ojú mí mà bà r'ibi
Rafiu, àbúrò mí ń gbà bọọlu nítá
Mo wọlé padà, màmá tí d'ojú bo'lẹ
Kàyéfì lójẹ', mo sáré pé bàbá mí
Adio, ó bà dákún, wá wó màmá rẹ
À ṣé ọlọjọ lódé o
Ńgbà t'ariwo tá, lo ńbí wà, "Kílódé?"
Kín to mọ, ẹsẹ tí pé
Shifau, pẹ'lú Mutairu béèrè sí ńké (omijé oh)
Wọn ní wọn ó le sìn màmá
Moní, "Kílódé?"
Wọn ní, "Ẹmí ó jáde tán" (ahh)
Kòfẹ fimí silẹ lọ ní
Ọjọ ìkíni lọ, ìkejì lọ
Ọjọ ìkẹta, Moria dágbere fún'ayé
Moriamo Alege (Moriamo)
Moriamo Alege (Moria oh)
Moriamo Alege
Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ
Moriamo Alege (Moriamo)
Moriamo Alege (Moriamo)
Moriamo Alege
Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ (Moriamo)
Ọrun re rẹ (Moriamo oh)
Moria dàgbere fún ayé
Odi'gbà, odi'gbere (Moriamo)
Mama Shifau, Mama Mutairu
Moriamo, ọmọ Alege, ọrun re rẹ
Mà ro'yin ẹ f'ọmọ mí (Moriamo oh)
Moriamo (Moriamo), Moriamo oh
Moriamo (Moriamo)
Moriamo Alege
Yeah, who's here?

⏱️ Synced Lyrics
[00:01.23] Ọmọ Adefi
[00:03.27] Ọmọ Adefa lókè Iresi
[00:04.45] (Moriamo Alege) (Moriamo)
[00:08.32] Ìyá bàbá mí, sún re
[00:10.42] Ní ilé àyé, 1980 something
[00:13.48] (The Beat Handle)
[00:15.49] Damilare, èmi l'àkọ́bí bàa mi, kí Qudus tó dì Qdot
[00:20.10] Ìyá àti bàbá mí tí Jáà ó tí pẹ
[00:22.73] Kín tó wa'yé lótí ní wọn le fẹ'ra wọn
[00:25.36] Okun ẹbí t'oba Jáà, welder kàn ó lé jo (Alagbe)
[00:29.96] K'Ọlọrun f'ọrun kẹ Moriamo, ìyá bàbá mí
[00:33.19] Moriamo, ọmọ Alege
[00:34.92] Ìyá má ń gb'ọmọ gẹ-gẹ ní
[00:37.48] Màmá ó gbé mí sílẹ̀ k'èyàn kan-kan tọju mí
[00:40.19] Moriamo, ọrun re
[00:42.46] Mí ó gbàgbé okò Alado o, l'ọnà Erugbabu
[00:45.63] Okò obi yí grandma tí fọ lójú kàn
[00:47.83] Bóyà ń torí obi tó mà tá ní muri kàn
[00:50.04] Ìyá yí tún padà s'oko, ada, t'ohun t'ọkọ ní
[00:53.17] Orí mí à wú to bà pé mí lọkọ' mí
[00:55.55] Ọjọ rí jẹ, pẹlú ọjọ rírí mú
[00:58.19] Màmá ma ń r'oka pẹlú ẹfọ Bọkọlu
[01:01.38] Omi odò là má ń mú (omi odò là má ń mú)
[01:04.53] Labúlé Ado, labúlé Ado oh (labúlé Ado)
[01:09.56] (Abúlé Ado) abúlé wá ó jìnà si Shagamu
[01:12.90] À ńpadà s'oko ní motor jamu (ó má ṣée)
[01:16.57] Màmá bà ń pariwo, "Damilare, ọmọlọmọ ní, ẹ bà ń gbé"
[01:20.58] Ó mà ṣeé, ó mà ṣee (ó mà ṣeé)
[01:23.21] Ọjọ yẹn ní mo mọ pé ìyá yí kọ lo bí mí
[01:26.67] Moriamo Alege (Moriamo)
[01:29.20] Moriamo Alege (Moria oh)
[01:31.85] Moriamo Alege, ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ
[01:36.74] Moriamo Alege (Moriamo)
[01:39.35] Moriamo Alege (Moria oh)
[01:41.87] Moriamo Alege
[01:43.57] Ìyá bàbá mí, ọrun rè rẹ (Moriamo)
[01:47.24] Ọrun re rẹ (Moria oh)
[01:49.87] Hmm, ọjọ re bí ana nígbà t'ikú wọlé dé
[01:53.77] Ìyá yí tí r'ikú lóṣe ní ń b'ode lọ
[01:57.28] K'ojú mí mà bà r'ibi
[01:58.73] Rafiu, àbúrò mí ń gbà bọọlu nítá
[02:01.33] Mo wọlé padà, màmá tí d'ojú bo'lẹ
[02:04.68] Kàyéfì lójẹ', mo sáré pé bàbá mí
[02:08.67] Adio, ó bà dákún, wá wó màmá rẹ
[02:12.42] À ṣé ọlọjọ lódé o
[02:13.97] Ńgbà t'ariwo tá, lo ńbí wà, "Kílódé?"
[02:16.12] Kín to mọ, ẹsẹ tí pé
[02:17.47] Shifau, pẹ'lú Mutairu béèrè sí ńké (omijé oh)
[02:21.10] Wọn ní wọn ó le sìn màmá
[02:22.98] Moní, "Kílódé?"
[02:23.73] Wọn ní, "Ẹmí ó jáde tán" (ahh)
[02:26.16] Kòfẹ fimí silẹ lọ ní
[02:28.56] Ọjọ ìkíni lọ, ìkejì lọ
[02:30.31] Ọjọ ìkẹta, Moria dágbere fún'ayé
[02:32.50] Moriamo Alege (Moriamo)
[02:34.94] Moriamo Alege (Moria oh)
[02:37.43] Moriamo Alege
[02:39.07] Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ
[02:42.52] Moriamo Alege (Moriamo)
[02:45.03] Moriamo Alege (Moriamo)
[02:47.64] Moriamo Alege
[02:49.23] Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ (Moriamo)
[02:52.89] Ọrun re rẹ (Moriamo oh)
[02:55.09] Moria dàgbere fún ayé
[02:57.89] Odi'gbà, odi'gbere (Moriamo)
[02:59.96] Mama Shifau, Mama Mutairu
[03:02.66] Moriamo, ọmọ Alege, ọrun re rẹ
[03:06.83] Mà ro'yin ẹ f'ọmọ mí (Moriamo oh)
[03:12.14] Moriamo (Moriamo), Moriamo oh
[03:17.04] Moriamo (Moriamo)
[03:19.22] Moriamo Alege
[03:21.73]
[03:25.47] Yeah, who's here?
[03:28.68]