Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Eyin Oluwa

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Alagbara โ€ข โฑ๏ธ 4:29
๐ŸŽต 1267 characters
โฑ๏ธ 4:29 duration
๐Ÿ†” ID: 9532928

๐Ÿ“œ Lyrics

Eje ka fope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipaa re po o e
Be laanu re duro o lai-lai

(Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga o-o-o-o-o (egbe ga)
Eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju o-o-o-o, halleluyah

Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti Kerubu, Serafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

(Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo
(Eyin Oluwa o), eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju ooo, halleluyah

Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori ododo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo (agbara re po pupo)

Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju oooo, halleluyah

Iyanju ogo re ti ki pade
Iyan wo ina re to kun fun abo
Onu gbogbo to da, o da won dara-dara
Ni ohun te angeli juba ni gbagbo

Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O n logaju oooo, halleluyah

Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo

Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O un logaju oooo, halleluyah

Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O n logaju oooo, halleluyah

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:19.38] Eje ka fope fun o e
[00:23.93] Iwa Olorun ni iyin to po
[00:28.75] Eru ipaa re po o e
[00:33.46] Be laanu re duro o lai-lai
[00:37.01] (Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
[00:43.15] Egbe e ga o-o-o-o-o (egbe ga)
[00:48.05] Eyin Oluwa o, halleluyah
[00:52.63] O hun logaju o-o-o-o, halleluyah
[00:58.35]
[01:07.19] Yin oun to fogbon da orun
[01:12.04] Yin oun to lewa ninu ogo
[01:16.79] Yin oun ti Kerubu, Serafu korin si o
[01:21.42] Oun re ru awon omi okun
[01:25.15] (Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
[01:31.29] Egbe e ga ooooo
[01:34.25] (Eyin Oluwa o), eyin Oluwa o, halleluyah
[01:40.74] O hun logaju ooo, halleluyah
[01:46.45]
[01:55.03] Nitori tori majemu ati pinlese
[01:59.99] Nitori tori ododo re ti kosaki
[02:04.75] Nitori irele ati fe re siwa
[02:09.66] Nitori agbara re topo pupo (agbara re po pupo)
[02:14.57] Eyin o Oluwa o, halleluyah
[02:19.22] Egbe e ga ooooo, halleluyah
[02:23.91] Eyin Oluwa o, halleluyah
[02:28.62] O hun logaju oooo, halleluyah
[02:34.09]
[02:43.24] Iyanju ogo re ti ki pade
[02:47.87] Iyan wo ina re to kun fun abo
[02:52.63] Onu gbogbo to da, o da won dara-dara
[02:57.62] Ni ohun te angeli juba ni gbagbo
[03:02.43] Eyin o Oluwa o, halleluyah
[03:07.21] Egbe e ga ooooo, halleluyah
[03:12.17] Eyin Oluwa o, halleluyah
[03:16.73] O n logaju oooo, halleluyah
[03:22.09]
[03:31.33] Yin in tinu tinu u re
[03:36.14] Yin in gbogbo to okan tara a
[03:41.19] Yin in bawon torun un o o o
[03:45.86] Oun loni ife e waju lo
[03:50.39] Eyin o Oluwa o, halleluyah
[03:55.24] Egbe e ga ooooo, halleluyah
[04:00.19] Eyin Oluwa o, halleluyah
[04:04.87] O un logaju oooo, halleluyah
[04:09.49] Eyin o Oluwa o, halleluyah
[04:14.19] Egbe e ga ooooo, halleluyah
[04:18.90] Eyin Oluwa o, halleluyah
[04:23.84] O n logaju oooo, halleluyah
[04:27.47]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings