Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Ikoko Oga Ogo

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Oruko Tuntun โ€ข โฑ๏ธ 5:50
๐ŸŽต 2026 characters
โฑ๏ธ 5:50 duration
๐Ÿ†” ID: 9532944

๐Ÿ“œ Lyrics

Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio Ma gbe abe ojiji re

Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio Ma gbe abe ojiji re

Ogun po oo ninu aiye
Awon to fori pamo sodo re nikan lo yege
Ibi nsele niwaju a wa o ni fara pa
Awa ngbe abe ojiji re

Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji re

Iji nja losan loru owuro aiye fere lewu ju oru lo
Eni to wa labe iye re nikan lole bo isho Olodumare
Nikan lo daju

Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio ma gbe abe ojiji re

Ogbon aiye ko kaiye jo Eeah!
Agbaraiye ko le kapa aiye
Aiye yiii bo eniyan aiye mole
Ipa toda aiye nikan lo ka

Oju eda ni tuuuuuu bi ti kiniun
Won se are won nibiiiiiii
Eda ti koro Ife tooooo
Beeni won dana yara won
Okan won gbe sirawon ooo
Ika won o kin ronu ki won to se ika
Abe ojiji nikan sa labo wa

Olorun ni abo abo wa
Olorun ni asa asa wa
Awa niran ti n saferi re Olorun Isreli
Abiye apa re lawa gbekele

Olorun ni abo abo wa
Olorun ni asa asa wa
Awa niran ti n saferi re Olorun Jakobu
Abiye apa re lawa gbekele

Egberun yio subu ni eba otun
Egbarun ni apa osi wa
Orun ki yio pawa nigba osan
Tabi osupa aiye nigba oru
Kiki oju wa nikan lawa o Ma fi ri
Toragbe abe ojiji re

Awa lo pamo oo
Nigba ewu
Awa lo di lamure e e
Nigba ogun
Awa lo gbe sejika re
Nigba ile n mi
Awa lo fi sabe iye e
Nigba ofa mbo
Oruko oluwaa
Lagbokan wa le
Awa lo gbe eee
Labe ojiji re

Awa lo pamo oo
Nigba ewu
Awa lo di lamure e e
Nigba ogun
Awa lo gbe sejika re
Nigba ile n mi
Awa lo fi sabe iye e

Nigba ofa mbo
Oruko oluwaa
Lagbokan wa le
Awa lo gbe eee
Labe ojiji re
Awa lo gbe eee
Labe ojiji oluwa
Awa lo fi sabe iye re
Abe ojiji re

Iwo to un gbe abe ojiji oluwa
Emi na gbeee
Labe ojiji re
Iwo to nfeee abo
Abe ojiji oluwa
Okan wa n gbeeee
Labe ojiji re

Awa lo n pamo o pamo
Labe ojiji oluwa
Awa lo ngbe eee
Abe ojiji re

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:19.24] Eni to joko nibikoko oga ogo
[00:23.17] Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
[00:27.12] Eni to joko nibikoko oga ogo
[00:31.25] Ni yio Ma gbe abe ojiji re
[00:36.15] Eni to joko nibikoko oga ogo
[00:39.88] Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
[00:43.98] Eni to joko nibikoko oga ogo
[00:48.17] Ni yio Ma gbe abe ojiji re
[00:52.38] Ogun po oo ninu aiye
[00:56.46] Awon to fori pamo sodo re nikan lo yege
[01:01.53] Ibi nsele niwaju a wa o ni fara pa
[01:05.82] Awa ngbe abe ojiji re
[01:09.35] Eni to joko nibikoko oga ogo
[01:13.75] Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
[01:18.09] Eni to joko nibikoko oga ogo
[01:21.96] Ni yio ma gbe abe ojiji re
[01:26.50] Iji nja losan loru owuro aiye fere lewu ju oru lo
[01:29.92] Eni to wa labe iye re nikan lole bo isho Olodumare
[01:41.48] Nikan lo daju
[01:43.13] Eni to joko nibikoko oga ogo
[01:47.08] Ni yio ma gbe abe ojiji Olodumare
[01:51.66] Eni to joko nibikoko oga ogo
[01:55.74] Ni yio ma gbe abe ojiji re
[02:17.47] Ogbon aiye ko kaiye jo Eeah!
[02:21.28] Agbaraiye ko le kapa aiye
[02:24.95] Aiye yiii bo eniyan aiye mole
[02:29.37] Ipa toda aiye nikan lo ka
[02:33.76] Oju eda ni tuuuuuu bi ti kiniun
[02:37.36] Won se are won nibiiiiiii
[02:45.87] Eda ti koro Ife tooooo
[02:50.43] Beeni won dana yara won
[02:54.69] Okan won gbe sirawon ooo
[02:58.73] Ika won o kin ronu ki won to se ika
[03:02.85] Abe ojiji nikan sa labo wa
[03:07.44] Olorun ni abo abo wa
[03:11.59] Olorun ni asa asa wa
[03:15.44] Awa niran ti n saferi re Olorun Isreli
[03:20.23] Abiye apa re lawa gbekele
[03:24.14] Olorun ni abo abo wa
[03:28.60] Olorun ni asa asa wa
[03:33.08] Awa niran ti n saferi re Olorun Jakobu
[03:36.98] Abiye apa re lawa gbekele
[03:58.02] Egberun yio subu ni eba otun
[04:02.23] Egbarun ni apa osi wa
[04:06.23] Orun ki yio pawa nigba osan
[04:10.62] Tabi osupa aiye nigba oru
[04:15.50] Kiki oju wa nikan lawa o Ma fi ri
[04:19.01] Toragbe abe ojiji re
[04:23.24] Awa lo pamo oo
[04:26.17] Nigba ewu
[04:27.05] Awa lo di lamure e e
[04:30.53] Nigba ogun
[04:30.92] Awa lo gbe sejika re
[04:33.48] Nigba ile n mi
[04:35.29] Awa lo fi sabe iye e
[04:37.80] Nigba ofa mbo
[04:39.54] Oruko oluwaa
[04:42.46] Lagbokan wa le
[04:43.87] Awa lo gbe eee
[04:45.99] Labe ojiji re
[04:48.43] Awa lo pamo oo
[04:50.28] Nigba ewu
[04:51.89] Awa lo di lamure e e
[04:55.06] Nigba ogun
[04:56.13] Awa lo gbe sejika re
[05:00.54] Nigba ile n mi
[05:01.85] Awa lo fi sabe iye e
[05:04.57] Nigba ofa mbo
[05:05.56] Oruko oluwaa
[05:07.19] Lagbokan wa le
[05:08.88] Awa lo gbe eee
[05:10.94] Labe ojiji re
[05:13.27] Awa lo gbe eee
[05:15.21] Labe ojiji oluwa
[05:16.98] Awa lo fi sabe iye re
[05:19.39] Abe ojiji re
[05:21.42] Iwo to un gbe abe ojiji oluwa
[05:25.77] Emi na gbeee
[05:28.51] Labe ojiji re
[05:30.26] Iwo to nfeee abo
[05:32.35] Abe ojiji oluwa
[05:34.06] Okan wa n gbeeee
[05:36.67] Labe ojiji re
[05:38.77] Awa lo n pamo o pamo
[05:40.84] Labe ojiji oluwa
[05:42.68] Awa lo ngbe eee
[05:44.77] Abe ojiji re
[05:46.79]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings