Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Mura

👤 Oladips 🎼 SUPERHERO ÀDÚGBÒ (The Memoir) ⏱️ 2:53
🎵 1726 characters
⏱️ 2:53 duration
🆔 ID: 9725932

📜 Lyrics

(The Dipsciples Music)
Ń ba tètè mọ
Ń ba ti mura silẹ (Maximum)
Mura silẹ
Hmm-hmm

Say I came into the world with my head and my two legs
I'll be 30 something in few years
Make nobody come put me under duress
Them say, "When e go happen?"
I tell them, "Few next-"
Mo gb'ori sókè, I look into Heaven
Malaika mímọ, oya, ẹ ṣí ilẹkun
Mo fẹ jade tàn, kí n ye yọ bi ẹkùn
Wọn ni lọ ilé babaláwo, make I do level

I swear, nobody saw me nígbà ti mo de o
Àìmọye free show wey them still no pay o
Kò s'ẹni ki mi pele nígbà ti mo ń ke o
Wey mama tell me, it will be okay o, ah-ah, ah
Ain't nobody tell me say this life na war
I for don come with my knife, cutlass, and gun

Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o, ń ba ti mura silẹ
Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ
Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o
Ń ba ti mura silẹ
Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ, ẹ-ẹ, ẹ
Ooh, ooh-ooh, ẹ-ẹ, ẹ

I know a lot of people way back, wey been sly me
Them say I no go see we kolebe wey go sign me
Anything wey them talk no consign me
Ṣùgbọn tò ba bi iya wọn ré, make them try me

Gọngọn àá sọ, kutupu ahu
Aye gbọ mi, mi o lé fumble
Soft life, kí n ma gbádùn
In this life, this life

I swear, nobody saw me nígbà ti mo de o
Àìmọye free show wey them still no pay o
Kò s'ẹni ki mi pele nígbà ti mo ń ke o
Wey mama tell me, it will be okay o, ah-ah, ah
Ain't nobody tell me say this life na war
I for don come with my knife, cutlass, and gun

Ń ba tètè mọ p'oju ogun láyé o, ń ba ti mura silẹ
Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ
Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o
Ń ba ti mura silẹ
Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ, ẹ-ẹ, ẹ
Hmm-hmm, ẹ-ẹ, ẹ

(hmm-hmm) hmm-hmm

⏱️ Synced Lyrics

[00:01.64] (The Dipsciples Music)
[00:04.82] Ń ba tètè mọ
[00:08.87] Ń ba ti mura silẹ (Maximum)
[00:14.51] Mura silẹ
[00:17.45] Hmm-hmm
[00:19.88] Say I came into the world with my head and my two legs
[00:23.53] I'll be 30 something in few years
[00:25.49] Make nobody come put me under duress
[00:28.15] Them say, "When e go happen?"
[00:29.26] I tell them, "Few next-"
[00:30.61] Mo gb'ori sókè, I look into Heaven
[00:33.59] Malaika mímọ, oya, ẹ ṣí ilẹkun
[00:35.97] Mo fẹ jade tàn, kí n ye yọ bi ẹkùn
[00:38.29] Wọn ni lọ ilé babaláwo, make I do level
[00:40.31] I swear, nobody saw me nígbà ti mo de o
[00:42.80] Àìmọye free show wey them still no pay o
[00:45.22] Kò s'ẹni ki mi pele nígbà ti mo ń ke o
[00:47.99] Wey mama tell me, it will be okay o, ah-ah, ah
[00:51.76] Ain't nobody tell me say this life na war
[00:57.42] I for don come with my knife, cutlass, and gun
[01:00.53] Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o, ń ba ti mura silẹ
[01:07.55] Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ
[01:10.51] Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o
[01:14.51] Ń ba ti mura silẹ
[01:17.64] Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ, ẹ-ẹ, ẹ
[01:23.20] Ooh, ooh-ooh, ẹ-ẹ, ẹ
[01:30.84] I know a lot of people way back, wey been sly me
[01:33.32] Them say I no go see we kolebe wey go sign me
[01:36.37] Anything wey them talk no consign me
[01:38.51] Ṣùgbọn tò ba bi iya wọn ré, make them try me
[01:40.53] Gọngọn àá sọ, kutupu ahu
[01:43.12] Aye gbọ mi, mi o lé fumble
[01:45.83] Soft life, kí n ma gbádùn
[01:48.01] In this life, this life
[01:51.04] I swear, nobody saw me nígbà ti mo de o
[01:53.58] Àìmọye free show wey them still no pay o
[01:56.00] Kò s'ẹni ki mi pele nígbà ti mo ń ke o
[01:58.58] Wey mama tell me, it will be okay o, ah-ah, ah
[02:02.68] Ain't nobody tell me say this life na war
[02:08.05] I for don come with my knife, cutlass, and gun
[02:11.14] Ń ba tètè mọ p'oju ogun láyé o, ń ba ti mura silẹ
[02:18.39] Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ
[02:21.14] Ń bá tètè mọ p'oju ogun láyé o
[02:25.31] Ń ba ti mura silẹ
[02:28.29] Mura silẹ, ẹ-ẹ, ẹ, ẹ-ẹ, ẹ
[02:34.05] Hmm-hmm, ẹ-ẹ, ẹ
[02:38.02] (hmm-hmm) hmm-hmm
[02:41.32]

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings