Anu Ni Mo Fe
๐ต 2287 characters
โฑ๏ธ 5:37 duration
๐ ID: 9760965
๐ Lyrics
Iwo nikan lo mo ju
To pe ju, to funfun ju
Iwo nikan lo ri inu to rokan gbogbo eniyan
Iwo nikan la o le sigba fun
Ta o le binu so, ta o le dalebi
Bo to run o lo n sola
To n pin ogo fun gbogbo eniyan
O se farau laye le
Iwo lo tun ran mose ko lo ba
Orile ede meji nbe ninu re
Aburo laa ma soga egbon
Jefta omo ale, o tun mu pada dolu omo
Ta a to dete re lojo idajo
Ojo anu ni ko foro mi si
Ta a to woju re lojo idajo
Ojo anu ni o foro mi si
Bi mo ba ranti gbolohun yen oo
Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun
Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si
Ise ma ko anu olorun ni
Ise eee ma ko oo anu olorun ni
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Jaakobu ni mo feran
Esau ni mo korira
Taleni to le mu o si iiii
Iwo lo daye olorun mi amo o o pin dede o
Awon kan gbenu Ile awon kan gbenu Igbo
Taleni to le mu o si
Awon kan wa omo were bi ibeji ko reni gbe
Taleni to le mu o gan
Samueli rele Jesse lati lol yanba titun fun isreali
Eliabu akobi lo koko jade
Tewa tewa ti giga ti giga
Samueli ro pe a ti roba oo
Baba mi je ko ye wipe mo ko oo
Ma woju re ma wo giga re
Mo ko
Eyan woju olorun wokan
Mo ko
Eyan le rewa ko ma raanu gba oo
Jeh olorun ooo
Awon mejeje koja niwaju woli
Sibe olorun ko won
Anu to sonu laye won
Davidi lo ri re
Ori ogo nbe ninu igbo oo
Ori ogo n toju ori aguntan
Bi mo ba ranti gbolohun yen
Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun
Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si
Ise ma ko ooo
Anu olorun ni
Ise mako oooo
Anu olorun ni
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baba Ise ko lowo
Olorun lohun ma gbe o ga
O so folorun pe o leni kankan
Banu ba de bo ba ranu gba
Ibi giga lo pe o ko wa logo re
Olorun ni wa fomo sile saye lo
O so folorun wipe baba mo ti dagba
To ba ranu gba oro re a ka ye logbon
Pe ba o ku oo ise o tan
Olorun sope ohun ma kole fun oo
O da olorun lohun pe o lowo iso
Seni to kole fun o teni yen o je nile lori
A se ooo pelu ase irorun
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu nikan lo le bamise ooo
Tori pe ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe oo
Baba ise ko lowo
(Aaaaaanu ni mofe)
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baby ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baba ise ko lowo
To pe ju, to funfun ju
Iwo nikan lo ri inu to rokan gbogbo eniyan
Iwo nikan la o le sigba fun
Ta o le binu so, ta o le dalebi
Bo to run o lo n sola
To n pin ogo fun gbogbo eniyan
O se farau laye le
Iwo lo tun ran mose ko lo ba
Orile ede meji nbe ninu re
Aburo laa ma soga egbon
Jefta omo ale, o tun mu pada dolu omo
Ta a to dete re lojo idajo
Ojo anu ni ko foro mi si
Ta a to woju re lojo idajo
Ojo anu ni o foro mi si
Bi mo ba ranti gbolohun yen oo
Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun
Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si
Ise ma ko anu olorun ni
Ise eee ma ko oo anu olorun ni
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Jaakobu ni mo feran
Esau ni mo korira
Taleni to le mu o si iiii
Iwo lo daye olorun mi amo o o pin dede o
Awon kan gbenu Ile awon kan gbenu Igbo
Taleni to le mu o si
Awon kan wa omo were bi ibeji ko reni gbe
Taleni to le mu o gan
Samueli rele Jesse lati lol yanba titun fun isreali
Eliabu akobi lo koko jade
Tewa tewa ti giga ti giga
Samueli ro pe a ti roba oo
Baba mi je ko ye wipe mo ko oo
Ma woju re ma wo giga re
Mo ko
Eyan woju olorun wokan
Mo ko
Eyan le rewa ko ma raanu gba oo
Jeh olorun ooo
Awon mejeje koja niwaju woli
Sibe olorun ko won
Anu to sonu laye won
Davidi lo ri re
Ori ogo nbe ninu igbo oo
Ori ogo n toju ori aguntan
Bi mo ba ranti gbolohun yen
Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun
Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si
Ise ma ko ooo
Anu olorun ni
Ise mako oooo
Anu olorun ni
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe ooo
Baba ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baba Ise ko lowo
Olorun lohun ma gbe o ga
O so folorun pe o leni kankan
Banu ba de bo ba ranu gba
Ibi giga lo pe o ko wa logo re
Olorun ni wa fomo sile saye lo
O so folorun wipe baba mo ti dagba
To ba ranu gba oro re a ka ye logbon
Pe ba o ku oo ise o tan
Olorun sope ohun ma kole fun oo
O da olorun lohun pe o lowo iso
Seni to kole fun o teni yen o je nile lori
A se ooo pelu ase irorun
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu nikan lo le bamise ooo
Tori pe ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe oo
Baba ise ko lowo
(Aaaaaanu ni mofe)
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baby ise ko lowo
Anu ni mofe
Anu ni mo bere
Anu ni mofe o
Baba ise ko lowo