Home ๐ŸŽฌ Bollywood ๐ŸŽต Pakistani ๐ŸŽค English Pop

Oruko Oluwa

๐Ÿ‘ค Tope Alabi โ€ข ๐ŸŽผ Oruko Tuntun โ€ข โฑ๏ธ 9:08
๐ŸŽต 2390 characters
โฑ๏ธ 9:08 duration
๐Ÿ†” ID: 9958121

๐Ÿ“œ Lyrics

Maa yin O, Olorun t'O dara, t'O n s'ohun gbogbo fun mi o
Emi o yin O, imole to n f'ona han mi oo e
Ore Re koja siso, o kamomo eee
Ona Re ma pe mi o, arinye ni o
eeee (titobi Oga nla)
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Awon t'orun n f'ogo fun Un, Elemi eda
O na'wo Re lat'orun ja aye o
O n rin lori igbi okun
Oruko Re nikan lo ko aje ya
Agbara Re nikan ni ko le pin
Ko s'eni to le gb'ogo Re pin lailai
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Gbogbo aye n wariri labe Re
Eda gbogbo o lo gba O loga
Ohun gbogbo to da lorun at'aye
Ko le ri'di agbara Re o ee
Won o le ri'di agbara Re o, Aseda mi
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Alade Ogo, iba Re o
Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Alagbara, Olododo, Atobiju lOluwa
Alaanu o lOluwa, oruko Re n gba ni la
Oruko Re n gbe ni ro, oruko Re n so ni d'oloro
Oloruko aperire (aperire apedahun loruko Jesu)
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oruko Re n ja fun ni
Oruko Re n gbe iku mi
Oruko Re n f'ona han ni
Oruko Re n t'aye se
Ibi gbo'ruko Re, o pare
Okunkun gbo o wole lo
Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
Ninu awon orun o, oruko Re niyi
Apeepetan, Oloruko pupo
Titi lailai, oruko Re ko le pin
Titi aye, oruko Re ko le pin
Oruko ti ko le baje, ni mo be'ri fun
Oruko ti o le pin, tion sir!
Oruko Oluwa o, ile iso
Oruko Oluwa ni ipa, agbara ni
Oruko, oruko, oruko, oruko, oruko nlanla
Emi ni, Ona
Otito, Iye
Ilekun, Kokoro
Imole, Ododo
Jesu Kristi, Messiah
Okuta aidigbolu, Odo aguntan rere
Apata ayeraye e

โฑ๏ธ Synced Lyrics

[00:19.45] Maa yin O, Olorun t'O dara, t'O n s'ohun gbogbo fun mi o
[00:26.37] Emi o yin O, imole to n f'ona han mi oo e
[00:36.05] Ore Re koja siso, o kamomo eee
[00:46.19] Ona Re ma pe mi o, arinye ni o
[00:53.98] Eeee (titobi Oga nla)
[00:58.93] Alade Ogo, iba Re o
[01:03.06] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[01:07.50] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[01:16.17] Alade Ogo, iba Re o
[01:20.38] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[01:24.31] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[01:33.17] Awon t'orun n f'ogo fun Un, Elemi eda
[01:37.00] O na'wo Re lat'orun ja aye o
[01:39.85] O n rin lori igbi okun
[01:41.74] Oruko Re nikan lo ko aje ya
[01:43.65] Agbara Re nikan ni ko le pin
[01:46.77] Ko s'eni to le gb'ogo Re pin lailai
[01:53.97] Alade Ogo, iba Re o
[01:58.64] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[02:03.07] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[02:11.77] Alade Ogo, iba Re o
[02:16.18] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[02:20.33] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[02:45.83] Gbogbo aye n wariri labe Re
[02:50.08] Eda gbogbo o lo gba O loga
[02:53.96] Ohun gbogbo to da lorun at'aye
[02:58.32] Ko le ri'di agbara Re o ee
[03:02.47] Won o le ri'di agbara Re o, Aseda mi
[03:11.72] Alade Ogo, iba Re o
[03:15.86] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[03:20.00] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[03:29.07] Alade Ogo, iba Re o
[03:33.03] Olorun to dara, iwa Re wu mi o e
[03:37.36] Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba
[04:00.56] Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
[04:08.51] Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
[04:12.49] Ninu awon orun o, oruko Re niyi
[04:16.04] Apeepetan, Oloruko pupo
[04:20.02] Titi lailai, oruko Re ko le pin
[04:28.17] Titi aye, oruko Re ko le pin
[04:35.62] Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
[04:43.13] Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
[04:47.14] Ninu awon orun o, oruko Re niyi
[04:51.03] Apeepetan, Oloruko pupo
[04:55.29] Titi lailai, oruko Re ko le pin
[05:02.79] Titi aye, oruko Re ko le pin
[05:10.89] Alagbara, Olododo, Atobiju lOluwa
[05:18.26] Alaanu o lOluwa, oruko Re n gba ni la
[05:26.07] Oruko Re n gbe ni ro, oruko Re n so ni d'oloro
[05:34.13] Oloruko aperire (aperire apedahun loruko Jesu)
[05:41.24] Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
[05:49.14] Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
[05:53.02] Ninu awon orun o, oruko Re niyi
[05:56.97] Apeepetan, Oloruko pupo
[06:00.78] Titi lailai, oruko Re ko le pin
[06:08.30] Titi aye, oruko Re ko le pin
[06:16.54] Oruko Re n ja fun ni
[06:20.30] Oruko Re n gbe iku mi
[06:24.27] Oruko Re n f'ona han ni
[06:28.16] Oruko Re n t'aye se
[06:32.07] Ibi gbo'ruko Re, o pare
[06:36.07] Okunkun gbo o wole lo
[06:43.43] Oluwa Oluwa, oruko Re niyi
[06:51.00] Ni gbogbo aye o, oruko Re niyi
[06:54.83] Ninu awon orun o, oruko Re niyi
[06:58.80] Apeepetan, Oloruko pupo
[07:02.62] Titi lailai, oruko Re ko le pin
[07:10.43] Titi aye, oruko Re ko le pin
[07:34.14] Oruko ti ko le baje, ni mo be'ri fun
[07:37.94] Oruko ti o le pin, tion sir!
[07:41.71] Oruko Oluwa o, ile iso
[07:45.46] Oruko Oluwa ni ipa, agbara ni
[07:53.28] Oruko, oruko, oruko, oruko, oruko nlanla
[07:57.56] Emi ni, Ona
[08:01.29] Otito, Iye
[08:04.67] Ilekun, Kokoro
[08:08.85] Imole, Ododo
[08:12.78] Jesu Kristi, Messiah
[08:16.04] Okuta aidigbolu, Odo aguntan rere
[08:20.62] Apata ayeraye e
[09:05.12]

โญ Rate These Lyrics

โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†โ˜†
Average: 0.0/5 โ€ข 0 ratings